July 8 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Kí Nìdí Tá A Fi Nílò Àwọn Ọlọ́pàá? Ààbò Táwọn Ọlọ́pàá Ń Pèsè—Ìrètí àti Ìbẹ̀rù Táwọn Èèyàn Ní Nípa Rẹ̀ Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ sí Àjọ Ọlọ́pàá Lọ́jọ́ Iwájú? Ìjọba Tó Fàyè Gba Onírúurú Ẹ̀sìn Láyé Ìgbà Tí Kò Sí Òmìnira Ìsìn Ìfiniṣẹrú—Kò Tí Ì Dáwọ́ Dúró Ọjọ́ Pẹ́ Táwọn Èèyàn Ti Ń Ṣakitiyan Láti Fòpin Sí Ìfiniṣẹrú Àkókò Tí Ìfiniṣẹrú Máa Dópin Ti Sún Mọ́lé! Àwọn Ohun Arùfé-Ìṣekúṣe-Sókè—Ṣé Nǹkan Ṣeréṣeré Lásán ni Wọ́n? Mímú Ara Aláìsàn Lọ́ Wọ́ọ́wọ́ Ṣáájú Iṣẹ́ Abẹ Kì Í Sábà Jẹ́ Kí Kòkòrò Àrùn Wọ Ojú Ọgbẹ́ Báwo Làjọgbé Èmi àti Alábàágbé Mi Ṣe Lè Wọ̀? “Ó Bọ́ Sákòókò Gẹ́lẹ́”