June 8 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Àwọn Ohun Tó Ń fa Ìṣòro—Láàárín Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Ìsìn Báwo Ni Àgbáálá Ayé àti Ìwàláàyè Ṣe Bẹ̀rẹ̀? Mímú Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Ìsìn Ṣọ̀kan Ǹjẹ́ Ó Yẹ Káwọn Kristẹni Máa Wàásù Fáwọn Ẹlòmíràn? Ǹjẹ́ O Mọ̀? Ètò Sayé Dọ̀kan—Ohun Táwọn Èèyàn Ń Fẹ́ Àtohun Tó Ń Bà Wọ́n Lẹ́rù Ṣé Ètò Sayé Dọ̀kan Lè Yanjú Àwọn Ìṣòro Wa Lóòótọ́? Ètò Sayé Dọ̀kan Tó Máa Ṣe Ọ́ Láǹfààní Iyọ̀—Ohun Èlò Ṣíṣeyebíye Báwo Ni Mo Ṣe Lè Rí Alábàágbé Tó Dára? “Títọ́jú Ìkókó Bíi Ti Ẹranko ‘Kangaroo’” Ṣé Ìyẹn Ló Máa Fòpin sí Ikú Àwọn Ìkókó Tí Oṣù Wọn Kò Pé? Àwọn Ibi Tí a ó Ti Ṣe Àpéjọ Àgbègbè “Àwọn Olùfi Ìtara Pòkìkí Ìjọba Ọlọ́run” Ti Ọdún 2002 sí 2003