June 8 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Kí Ló Fà Á Tí Ọ̀pọ̀ Èèyàn Fi Dá Wà? Bíborí Ìṣòro Dídá Wà Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Ẹnikẹ́ni Ò Ní Dá Wà Mọ́ Ǹjẹ́ O Mọ̀? Ọjọ́ Pẹ́ Táráyé Ti Ń Gbógun Ti Àrùn Ibi Táráyé Ṣẹ́gun Àrùn Dé àti Ibi Tó Kù Sí Ayé Kan Níbi Tí Kò Ti Ní Sí Àrùn Ṣé Ẹní Bá Ń Ṣàníyàn Ò Nígbàgbọ́ Ni? Wíwo Ayé Kí Ló Fà Á Tó Fi Ń Hu Irú Ìwà Yìí sí Mi? Kí Ló Dé Tí Ọ̀fìnkìn Tí Nǹkan Tó Ń Kù Ń Fà fi Ń Yọ Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́nu? Ó Yẹ Ká Kó Ahọ́n Wa Níjàánu Bíi Tẹṣin “Àdúrà Mi Gbà”