November 8 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ṣé Ìṣòro Ni Pé Kéèyàn Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀? Kí Ló Ń Jẹ́ Kéèyàn Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀? Kí Lẹni Tó Bá Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀ Lè Rí Ṣe Sí I? Ǹjẹ́ Àǹfààní Kankan Wà Nínú Kéèyàn Dín Bó Ṣe Sanra Jọ̀kọ̀tọ̀ Kù? Báwo Ni Kíkọ́ Ọmọ Láti Kékeré Ti Ṣe Pàtàkì Tó? Bó Ṣe Ṣe Pàtàkì Tó Pé Kó O Tọ́ Ọmọ Rẹ Ojúṣe Rẹ Gẹ́gẹ́ bí Òbí Àtikékeré Ni Wọ́n Ti Kọ́ Mi Láti Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run Fífi Ìbáwí Ọlọ́run Tọ́ Àwọn Ọmọ Báwo Ni Mo Ṣe Lè Sọ Ohun Tó Wà Lọ́kàn Mi fún Un? Àwọn Àǹfààní Tó Wà Nínú Kíkàwé Fáwọn Ọmọdé Wọ́n Lè Tu Àwọn Tí Ọ̀fọ̀ Ṣẹ̀ Nínú