October Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ṣé Tẹlifíṣọ̀n Ń Jani Lólè Àkókò Lóòótọ́? Tẹlifíṣọ̀n “Olùkọ́ Tó Ń kọ́ Wa Láìmọ̀” Béèyàn Ṣe Lè Pinnu Ìwọ̀n Táá Máa Wò Bó O Ṣe Lè Ran Ọmọbìnrin Rẹ Lọ́wọ́ Láti Múra Sílẹ̀ De Ìgbà Tó Máa Bẹ̀rẹ̀ sí Í Ṣe Nǹkan Oṣù Ọmọdé Kan Tí Ìgbàgbọ́ Ẹ̀ Lágbára Wíwo Ayé Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ran Àwọn Tó Di Aláìní Lọ́wọ́? Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ìṣẹ̀dá? Ṣé Ohun Tó Bá Wù Ọ́ Lo Lè Gbà Gbọ́? Ǹjẹ́ O Lè Ran Àwọn Òkú Lọ́wọ́? Ṣáwọn Èèyàn Máa Ń Di Áńgẹ́lì Lẹ́yìn Tí Wọ́n Bá Kú? Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Ta Ko Àkọsílẹ̀ Inú Jẹ́nẹ́sísì? Kí Ni Ìdáhùn Rẹ? Àràádọ́ta Ọ̀kẹ́ Èèyàn Ló Máa Lọ Síbẹ̀ Ṣé Ìwọ Náà Á Lọ?