April Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí O Lè Mú Kí Ìlera Rẹ Dára Sí I Ohun 1—Máa Ṣọ́ Oúnjẹ Jẹ Ohun 2—Máa Ṣìkẹ́ Ara Rẹ Ohun 3—Má Ṣe Máa Jókòó Gẹlẹtẹ Sójú Kan Ohun 4—Ṣọ́ra fún Ohun Tó Lè Ṣàkóbá fún Ìlera Rẹ Ohun 5—Ran Ara Rẹ àti Ìdílé Rẹ Lọ́wọ́ Máa Ṣe Àwọn Nǹkan Tó Máa Jẹ́ Kí Ìlera Rẹ Dára Sí I Àwọn Ewu Wo Ló Wà Nínú Sìgá Mímu Tó Yẹ Kí N Mọ̀? Ohun Tó Dára Jù Lọ Ni Mo Fi Ayé Mi Ṣe Ǹjẹ́ Fífi Ìyà Jẹ Ara Ẹni Lè Múni Sún Mọ́ Ọlọ́run? Kí Nìdí Táwọn Òbí Mi Kì Í Jẹ́ Kí N Gbádùn Ara Mi? Ohun Tó Lè Dáàbò Bo Àwọn Àgbàlagbà Ṣé Mo Ti Sọ Àwọn Ohun Tó Ń Gbé Ìsọfúnni Jáde Di Bárakú? Ǹjẹ́ Ìgbàgbọ́ àti Àròjinlẹ̀ Bára Tan? Oorun Báwo Ló Ti Ṣe Pàtàkì Tó? Ǹjẹ́ O Ní Àwọn Àfojúsùn Tí Ọwọ́ Rẹ Lè Tẹ̀? “Ẹ Ṣeun Tẹ́ Ẹ Fi Bàbá Tó Nífẹ̀ẹ́ Wa Hàn Mí”