No. 1 Ǹjẹ́ Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Ọkàn Wa Máa Balẹ̀? Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí OHUN TÓ JẸ́ ÌṢÒRO Kò Sí Ààbò àti Ìfọ̀kànbalẹ̀ OHUN TÓ YẸ KÁ MỌ̀ Ó Yẹ Ká Mọ Ohun Tó Ń Fa Ìṣòro Náà BÁ A ṢE LÈ YANJÚ ÌṢÒRO NÁÀ Ẹ̀kọ́ Nípa Ìwà Ọmọlúwàbí WỌ́N BORÍ ÌṢÒRO WỌN Ìtàn Ricardo àti Andres ÌJỌBA TÓ MÁA YANJÚ ÌṢÒRO NÁÀ “Àlàáfíà Kì Yóò Lópin” BÍ ÌṢÒRO NÁÀ ṢE MÁA YANJÚ PÁTÁPÁTÁ Àlàáfíà Máa Pọ̀ Yanturu Lábẹ́ Ìjọba Ọlọ́run Kí Lèrò Rẹ?