Ọkunrin Titobilọla Julọ (gt) Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé sí Koko Ẹ̀kọ́ Inu Iwe Ọkunrin Titobilọla Julọ Ti O Tii Gbé Ayé Rí Awọn Ilẹ̀ Nibi Ti Jesu Ti Rìn Awọn Ihin-iṣẹ Lati Ọrun Wá A Bọla Fun Un Ṣaaju Ìbí Rẹ̀ A Bí Atọ́nàṣe Naa O Lóyún Ṣugbọn Kò Ṣe Igbeyawo Ìbí Jesu—Nibo ati Nigba Wo? Ọmọ Ileri Naa Jesu ati Awọn Aworawọ Àsálà Kuro Lọwọ Òǹrorò Kan Ibẹrẹpẹpẹ Igbesi-aye Idile Jesu Awọn Irin Ajo si Jerusalẹmu Johanu Pa Ọ̀nà Mọ́ Baptism Jesu Kikẹkọọ Lati Inu Awọn Ìdẹwò Jesu Awọn Ọmọ-ẹhin Jesu Akọkọ Iṣẹ Iyanu Akọkọ Ti Jesu Ṣe Itara fun Ijọsin Jehofa Kíkọ́ Nikodemu Lẹkọọ Johanu Ńpẹ̀dín, Jesu Nbisii Kíkọ́ Obinrin Ara Samaria Kan Lẹkọọ Iṣẹ Iyanu Keji ni Kana Ninu Sinagọgu Ilu Ibilẹ Jesu A Pe Awọn Ọmọ-ẹhin Mẹrin Iṣẹ Iyanu Pupọ Sii ni Kapanaomu Ìdí Ti Jesu Fi Wá sí Aye Ìyọ́nú fun Adẹ́tẹ̀ Kan Lẹhin Dídé Ilé ní Kapanaomu Pípe Matiu A Bi Í Leere Nipa Ààwẹ̀ Ṣíṣe Awọn Iṣẹ́ Rere ní Sabaati Dídá Awọn Olùfisùn Rẹ̀ Lóhùn Yíya Ọkà ní Sabaati Ki Ni Ohun Tí Ó Bófinmu ní Sabaati? Mímú Asọtẹlẹ Aisaya Ṣẹ Yíyan Awọn Apọsiteli Rẹ̀ Ìwàásù Tí O Lókìkí Julọ Tí A Tíì Fúnni Rí Ìgbàgbọ́ Títóbi Ọ̀gágun Kan Jesu Lé Ẹ̀dùn Ọkàn Opó kan Lọ Johanu Ha Ṣàìní Ìgbàgbọ́ Bí? Awọn Agbéraga ati Awọn Onirẹlẹ Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Kan Nipa Àánú Ẹni Ti Àríyànjiyàn Dale Lori Jesu Bá Awọn Farisi Wi Lọna Lilekoko Kíkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Pẹlu Awọn Àkàwé Mímú Ìjì Apaniláyà Kan Dákẹ́ Ọmọ-ẹhin kan Tí A Kò Ronúkàn Obinrin Naa Fọwọ́kàn Ẹ̀wù Rẹ̀ Omijé Yípadà di Ayọ̀ Ńlá Fífi Ilé Jairu Silẹ ati Pípadà Ṣèbẹ̀wò sí Nasarẹti Ìrìn Àjò Iwaasu Miiran ní Galili Ìmúrasílẹ̀ Lati Dojúkọ Inúnibíni Ìṣìkàpànìyàn Nigba Àpèjẹ Ọjọ́-ìbí Kan Jesu Bọ́ Ẹgbẹẹgbẹrun Lọna Iṣẹ́-ìyanu Olùṣàkóso Ti O Ju Ẹda Eniyan Lọ kan Tí A Nífẹ̀ẹ́ Sí “Burẹdi Tootọ Lati Ọrun” Ọ̀pọ̀ Ọmọ-ẹhin Pada Lẹhin Jesu Ki Ni Ńsọ Ènìyàn di Ẹlẹ́gbin? Ìyọ́nú fun Awọn Ti A Npọnloju Awọn Ìṣù Burẹdi ati Ìwúkàrà Ta Ni Jesu Jẹ́ Niti Gidi? Ifihan Ṣaaju Ògo Ijọba Kristi A Mú Ọmọdekunrin Tí O Ni Ẹ̀mí Buburu Láradá Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n kan Nipa Ìrẹ̀lẹ̀ Ìmọ̀ràn Atọ́nisọ́nà Siwaju Síi Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n kan Nipa Ìdáríjì Ìrìn Àjò Bòókẹ́lẹ́ kan sí Jerusalẹmu Ní Àjọ-àríyá Awọn Àgọ́-ìsìn Wọn Kùnà Lati Fi Àṣẹ Ọba Mú Un Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Siwaju Síi ní Ọjọ́ Keje Àríyànjiyàn Lori Ipò Jijẹ Baba Mímú Ọkunrin kan Tí A Bí Ní Afọ́jú Láradá Awọn Farisi Mọ̀ọ́mọ̀ Ṣaigbagbọ Jesu Rán 70 naa Jáde Ará Samaria Aládùúgbò Rere Kan Ìmọ̀ràn fun Mata, ati Ìtọ́ni Lórí Adura Orísun Ayọ̀ Jíjẹun Pẹlu Farisi Kan Àríyànjiyàn Lori Ogún Ẹ Wà Ní Ìmúratán! Orílẹ̀-èdè kan Sọnù, Ṣugbọn Kii Ṣe Gbogbo Rẹ̀ Awọn Ọgbà-àgùtàn ati Olùṣọ́-àgùtàn Ìgbìdánwò Siwaju Sii Lati Pa Jesu Jesu Lẹẹkan Sii Forile Jerusalẹmu Farisi kan Ṣe É Lálejò Ẹrù-iṣẹ́ Jíjẹ́ Ọmọ-ẹ̀hìn Wíwá Eyi Tí Ó Sọnù Kiri Ìtàn Ọmọkunrin Tí Ó Nù Pèsè fun Ọjọ́ Ọ̀la Pẹlu Ọgbọ́n Ti O Ṣeemulo Ọkunrin Ọlọ́rọ̀ Naa ati Lasaru Iṣẹ́-àpèrán Aláàánú kan Sí Judia Ireti Ajinde Nigba Ti A Jí Lasaru Dìde A Mú Awọn Adẹ́tẹ̀ Mẹ́wàá Láradá Lákòókò Ìrìn Àjò Jesu Tí Ó Kẹhin sí Jerusalẹmu Nigba Ti A Bá Ṣí Ọmọkunrin Ènìyàn Payá Ìdí fun Adura ati fun Ìrẹ̀lẹ̀ Awọn Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Lórí Ìkọ̀sílẹ̀ ati Lórí Ìfẹ́ fun Awọn Ọmọ Jesu ati Ọ̀dọ́ Olùṣàkóso Kan Ti O Lọ́rọ̀ Awọn Òṣìṣẹ́ Ninu Ọgbà Àjàrà Awọn Ọmọ-ẹhin Ńjiyàn bí Ikú Jesu ti Ńsúnmọ́lé Jesu Kọ́nilẹ́kọ̀ọ́ ní Jẹriko Àkàwé Nipa Mina Ní Bẹtani, ní Ilé Simoni Kristi Wọ Jerusalẹmu Pẹlu Ayọ̀ Ìṣẹ́gun Bíbẹ Tẹmpili Wò Lẹẹkan Sii A Gbọ́ Ohùn Ọlọrun Ní Ìgbà Kẹta Ìbẹ̀rẹ̀ Ọjọ́ Tí Ó Ṣekókó Naa Awọn Àkàwé Ọgbà Àjàrà Tú Wọn Fó Àkàwé Nipa Àsè Ìgbéyàwó Wọn Kùnà Lati Dẹkùn Mú Jesu Jesu Fi Awọn Alátakò Rẹ̀ Bú Iṣẹ́-òjíṣẹ́ ní Tẹmpili Parí Àmì Awọn Ọjọ Ikẹhin Ìrékọjá Ìgbẹ̀hìn fun Jesu Kù Sí Dẹ̀dẹ̀ Ìrẹ̀lẹ̀ Lakooko Ìrékọjá Ikẹhin Àsè Alẹ́ Ìṣe-ìrántí Ìjiyàn kan Bẹ Silẹ Mimura Awọn Apọsiteli Silẹ fun Igberalọ Rẹ̀ Irora Ẹdun Ninu Ọgba Naa Ìtáṣìrí ati Ìfàṣẹ Ọba Muni A Mú Un Lọ Sọdọ Anasi, Lẹhin Naa Sọdọ Kaifa Ìsẹ́ni Ninu Àgbàlá Niwaju Sanhẹdrin, Lẹhin Naa Sọdọ Pilatu Lati Ọ̀dọ̀ Pilatu Sọdọ Hẹrọdu A sì Tún Rán an Pada “Ẹ Wò Ó! Ọkunrin Naa!” A Fà Á Lé Wọn Lọwọ Wọn Si Mu Un Lọ Ijẹrora Lori Òpó-igi “Dajudaju Ọmọkunrin Ọlọrun Ni Eyi” A Sin ín ni Friday—Iboji Rẹ̀ Ṣofo ni Sunday Jesu Walaaye! Awọn Ifarahan Siwaju Sii Ni Òkun Galili Awọn Ifarahan Ikẹhin, ati Pẹntikọsi 33 C.E. Ni Ọwọ́ Ọtun Ọlọrun Jesu Pari Gbogbo Ohun Ti Ọlọrun Beere Fun