ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ọ̀sẹ̀ Yìí
September 8-14
Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́—2025 | September

SEPTEMBER 8-14

ÒWE 30

Orin 136 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

1. “Má Ṣe Fún Mi Ní Òṣì Tàbí Ọrọ̀”

(10 min.)

Ọrọ̀ kò lè fúnni ní ayọ̀ tòótọ́, àmọ́ téèyàn bá gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, á ní ayọ̀ tòótọ́ (Owe 30:8, 9; w18.01 24-25 ¶10-12)

Olójúkòkòrò kì í ní ìtẹ́lọ́rùn (Owe 30:15, 16; w17.05 26 ¶15-17)

Tó o bá ń tẹ̀ lé ìlànà Bíbélì, o ò ní tọrùn bọ gbèsè, ọkàn ẹ á sì balẹ̀ (Owe 30:24, 25; w11 6/1 10 ¶3)

Inú ìyá kan ń dùn bó ṣe ń rí i tí ọmọbìnrin ẹ̀ ń ju owó sínú ìgò kan.

OHUN TẸ́ Ẹ LÈ ṢE NÍGBÀ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ: Ẹ jíròrò bí ọ̀rọ̀ owó ṣe máa ń rí lára ẹnì kọ̀ọ̀kan yín.—w24.06 13 ¶18.

2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì

(10 min.)

  • Owe 30:26—Kí la rí kọ́ lára àwọn gara orí àpáta? (w09 4/15 17 ¶11-13)

  • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?

3. Bíbélì Kíkà

(4 min.) Owe 30:1-14 (th ẹ̀kọ́ 2)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa

(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Fi Ilé Ìṣọ́ No. 1 2025 wàásù fẹ́nì kan. (lmd ẹ̀kọ́ 1 kókó 3)

5. Pa Dà Lọ

(4 min.) ÌWÀÁSÙ NÍBI TÍ ÈRÒ PỌ̀ SÍ. (lmd ẹ̀kọ́ 9 kókó 3)

6. Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́

(4 min.) Àsọyé. ijwbq àpilẹ̀kọ 102—Àkòrí: Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Tẹ́tẹ́ Títa? (th ẹ̀kọ́ 7)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Orin 80

7. Má Ṣe Jẹ́ Kí Ohun Tí Ayé Ń Pè Ní Àlàáfíà Tàn Ẹ́ Jẹ!—Chibisa Selemani

(5 min.) Ìjíròrò.

Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé:

  • Kí lo rí kọ́ nínú ìrírí Arákùnrin Selemani tó máa jẹ́ kó o ṣèpinnu táá fi ẹ́ lọ́kàn balẹ̀, tí wàá sì ní ìtẹ́lọ́rùn?

8. Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September

(10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo FÍDÍÒ náà.

9. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ

(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 16-17

Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.) | Orin 128 àti Àdúrà

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2025 | June

Àpilẹ̀kọ fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ 27: September 8-14, 2025

20 Ran Ẹni Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́wọ́ Kó Lè Sin Jèhófà

Àfikún

Àwọn àpilẹ̀kọ míì tó wà nínú ìwé yìí

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́