-
Apa 1Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 1
Bíbélì ni Ọlọ́run fi ń bá wa sọ̀rọ̀. 2 Tímótì 3:16
Ibi gbogbo ni àwọn èèyàn ti ń tẹ́tí sí Ọlọ́run. Mátíù 28:19
-
-
Apa 2Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 2
Jèhófà ló dá ohun gbogbo tó wà ní ọ̀run . . . àti lórí ilẹ̀ ayé. Sáàmù 83:18; Ìfihàn 4:11
-
-
Apa 3Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 3
Àìmọye nǹkan rere ni Jèhófà fún Ádámù àti Éfà. Jẹ́nẹ́sísì 1:28
Ọlọ́run sọ pé wọn kò gbọ́dọ̀ jẹ èso ọ̀kan lára àwọn igi tó wà nínú ọgbà náà. Jẹ́nẹ́sísì 2:16, 17
-
-
Apa 4Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 4
Ádámù àti Éfà ṣàìgbọràn sí Ọlọ́run, wọ́n sì kú. Jẹ́nẹ́sísì 3:6, 23
Àwọn tó ti kú dà bí erùpẹ̀ lásán. Jẹ́nẹ́sísì 3:19
-
-
Apa 5Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 5
Ìwà burúkú ni àwọn èèyàn tó pọ̀ jù nígbà ayé Nóà ń hù. Jẹ́nẹ́sísì 6:5
Nóà tẹ́tí sí Ọlọ́run, ó sì kan ọkọ̀ áàkì. Jẹ́nẹ́sísì 6:13, 14, 18, 19, 22
-
-
Apa 2Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 2
Ọlọ́run pa àwọn èèyàn burúkú yẹn run, àmọ́ ó dá Nóà àti ìdílé rẹ̀ sí. Jẹ́nẹ́sísì 7:11, 12, 23
Ọlọ́run ṣì tún máa pa àwọn ẹni burúkú run, á sì dá àwọn ẹni rere sí. Mátíù 24:37-39
-
-
Apa 7Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 7
Jèhófà rán Jésù wá sí ayé. 1 Jòhánù 4:9
Ohun rere ni Jésù ṣe, àmọ́ àwọn èèyàn kórìíra rẹ̀. 1 Pétérù 2:21-24
-
-
Apa 8Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 8
Jésù kú torí ká lè ní ìyè. Jòhánù 3:16
Ọlọ́run jí Jésù dìde, ó sì sọ ọ́ di Ọba Ìjọba Ọlọ́run. Dáníẹ́lì 7:13, 14
-
-
Apa 9Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 9
Àwọn wàhálà tó ń ṣẹlẹ̀ nínú ayé jẹ́ ká mọ̀ pé Ìjọba Ọlọ́run máa tó dé. Lúùkù 21:10, 11; 2 Tímótì 3:1-5
Ìjọba Ọlọ́run máa mú gbogbo ìwà ibi kúrò. 2 Pétérù 3:13
-
-
Apa 10Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 2
Ọlọ́run máa jí èyí tó pọ̀ jù lára àwọn tó ti kú dìde sí ayé. Ìṣe 24:15
Ìjọba Ọlọ́run máa fòpin sí gbogbo ìyà tó ń jẹ aráyé. Ìfihàn 21:3, 4
-
-
Apa 11Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 11
Ó dájú pé Ọlọ́run máa ń gbọ́ àdúrà wa. 1 Pétérù 3:12
A lè mẹ́nu kan ọ̀pọ̀ nǹkan nínú àdúrà wa. 1 Jòhánù 5:14
-
-
Apa 12Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 12
Ìfẹ́ ló máa jẹ́ kí ìdílé ní ayọ̀. Éfésù 5:33
Ẹ jẹ́ onínúure àti olóòótọ́, ẹ má ṣe ya ọ̀dájú, ẹ má sì jẹ́ aláìṣòótọ́. Kólósè 3:5, 8-10
-
-
Apa 13Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 13
Máa sá fún ohun tó burú. 1 Kọ́ríńtì 6:9, 10
Máa ṣe ohun tó dára. Mátíù 7:12
-
-
Apa 14Tẹ́tí sí Ọlọ́run
-
-
Apa 14
Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni kí o dúró sí. 1 Pétérù 5:6-9
Yan ohun tí ó tọ́, ìyẹn ni pé kí o tẹ́tí sí Ọlọ́run. Mátíù 7:24, 25
-