-
Ugarit—Ìlú Ìgbàanì Tó Wà Níbi Tí Ìjọsìn Báálì Ti Gbilẹ̀Ilé Ìṣọ́—2003 | July 15
-
-
Ó dà bíi pé ewì àwọn ará Ugarit kan sọ pé síse ọmọ ewúrẹ́ nínú wàrà jẹ́ ara ààtò ìbímọlémọ tó wọ́pọ̀ nínú ẹ̀sìn àwọn ará Kénáánì. Bẹ́ẹ̀, ohun tá a pa láṣẹ fáwọn ọmọ Ísírẹ́lì nínú Òfin Mósè ni pé: “Ìwọ kò gbọ́dọ̀ se ọmọ ẹran nínú wàrà ìyá rẹ̀.”—Ẹ́kísódù 23:19.
-
-
Ugarit—Ìlú Ìgbàanì Tó Wà Níbi Tí Ìjọsìn Báálì Ti Gbilẹ̀Ilé Ìṣọ́—2003 | July 15
-
-
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 26]
Ọ̀rọ̀ ewì àwọn ará Ugarit kan lè jẹ́ ká rí ìdí ohun tó wà nínú Ẹ́kísódù 23:19
[Credit Line]
Musée du Louvre, Paris
-