-
“Pa Àwọn Àṣẹ Mi Mọ́ Kí o Sì Máa Bá a Lọ Ní Wíwà Láàyè”Ilé Ìṣọ́—2000 | November 15
-
-
Èé ṣe tó fi yẹ ká fiyè sí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Ìwé Mímọ́ ká sì tún jẹ́ kí ọgbọ́n àti òye sún mọ́ wa dáadáa? Ká lè “máa ṣọ́ [ara wa] lọ́wọ́ obìnrin tí ó jẹ́ àjèjì, lọ́wọ́ ọmọ ilẹ̀ òkèèrè tí ó ti mú kí àwọn àsọjáde rẹ̀ dùn mọ̀nràn-ìn mọnran-in.” (Òwe 7:5) Bẹ́ẹ̀ ni o, ṣíṣe bẹ́ẹ̀ á dáàbò bò wá lọ́wọ́ àwọn ọ̀rọ̀ dídùn àti àwọn ọ̀nà ayíniléròpadà ti àjèjì kan—ìyẹn ẹnì kan tó jẹ́ oníṣekúṣe.a
-
-
“Pa Àwọn Àṣẹ Mi Mọ́ Kí o Sì Máa Bá a Lọ Ní Wíwà Láàyè”Ilé Ìṣọ́—2000 | November 15
-
-
a Ọ̀rọ̀ náà “àjèjì” ni a lò fún àwọn tó sọ ara wọn dàjèjì sí Jèhófà nípa yíyí padà kúrò nínú àwọn Òfin rẹ̀. Ìdí nìyẹn táa fi pe oníṣekúṣe obìnrin kan, irú bí aṣẹ́wó kan, ní “obìnrin tí ó jẹ́ àjèjì.”
-