ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jèhófà Mú Ẹ̀mí Àwọn Ẹni Rírẹlẹ̀ Sọ Jí
    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kejì
    • 6 Ibi gbogbo ni Júdà ti ń bọ̀rìṣà, ì báà ṣabẹ́ igi, ì báà ṣàfonífojì, ì báà ṣorí àwọn òkè, tàbí nínú ìlú wọn. Àmọ́ gbogbo rẹ̀ pátá ni Jèhófà rí, tó sì gbẹnu Aísáyà táṣìírí rẹ̀, ó ní: “Orí òkè ńlá gíga tí ó sì gbé sókè ni o gbé ibùsùn rẹ kalẹ̀ sí. Ibẹ̀ pẹ̀lú ni o gòkè lọ láti rú ẹbọ. Ẹ̀yìn ilẹ̀kùn àti òpó ilẹ̀kùn ni o gbé ìrántí rẹ kalẹ̀ sí.” (Aísáyà 57:7, 8a) Orí àwọn ibi gíga ni Júdà tẹ́ ibùsùn àìmọ́ nípa tẹ̀mí rẹ̀ sí, ibẹ̀ ló sì ti ń rú àwọn ẹbọ sí àwọn òrìṣà ilẹ̀ òkèèrè.a Kódà àwọn ilé àdáni pàápàá ní òrìṣà lẹ́yìn àwọn ilẹ̀kùn àti òpó ilẹ̀kùn wọn.

  • Jèhófà Mú Ẹ̀mí Àwọn Ẹni Rírẹlẹ̀ Sọ Jí
    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà—Ìmọ́lẹ̀ fún Gbogbo Aráyé, Apá Kejì
    • a Ó ṣeé ṣe kí ohun tí a pè ní “ibùsùn” níhìn-ín máa tọ́ka sí pẹpẹ tàbí sí ojúbọ. Pípè é ní ibùsùn jẹ́ ìránnilétí pé irú ìjọsìn bẹ́ẹ̀ jẹ́ ìwà aṣẹ́wó nípa tẹ̀mí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́