ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìfẹ́
    Jí!—2018 | No. 1
    • Jésù Kristi kọ́ wa ní àwọn ìlànà pàtàkì nípa ìgbéyàwó. Bí àpẹẹrẹ, ó sọ pé: “ ‘Ọkùnrin yóò fi baba rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, yóò sì fà mọ́ aya rẹ̀, àwọn méjèèjì yóò sì di ara kan’ . . . Nítorí náà, ohun tí Ọlọ́run ti so pọ̀, kí ènìyàn kankan má ṣe yà á sọ́tọ̀.” (Mátíù 19:​5, 6) Ó kéré tán, ìlànà pàtàkì méjì wà nínú ọ̀rọ̀ tí Jésù sọ yìí.

  • Ìfẹ́
    Jí!—2018 | No. 1
    • “OHUN TÍ ỌLỌ́RUN TI SO PỌ̀.” Ọlọ́run ka ìgbéyàwó sí àjọṣe mímọ́. Tí tọkọtaya bá ní irú èrò yìí, wọ́n á máa sapá láti mú kí ìdè ìgbéyàwó wọn túbọ̀ lágbára sí i. Tí wọ́n bá tiẹ̀ kojú ìṣòro, wọn kò ní máa wá ọ̀nà láti tú ìgbéyàwó wọn ká. Ìfẹ́ wọn á lágbára gan-an. Tọkọtaya tó bá ní irú ìfẹ́ bẹ́ẹ̀ á “máa mú ohun gbogbo mọ́ra,” wọ́n á sì jọ wá ojútùú sí ìṣòro wọn, kí àláàfíà àti ìṣọ̀kan lè wà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́