ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jésù Dáhùn Ìbéèrè Ọ̀dọ́kùnrin Ọlọ́rọ̀ Kan
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
    • Jésù wá sọ pé: “Àmọ́ ọ̀pọ̀ àwọn ẹni àkọ́kọ́ máa di ẹni ìkẹyìn, àwọn ẹni ìkẹyìn sì máa di ẹni àkọ́kọ́.” (Mátíù 19:30) Kí ló ní lọ́kàn?

      Ọ̀dọ́kùnrin ọlọ́rọ̀ yẹn wà lára àwọn “ẹni àkọ́kọ́,” torí pé ó jẹ́ ọ̀kan lára aṣáájú àwọn Júù. Ó máa ń pa òfin Ọlọ́run mọ́, torí ẹ̀, tó bá di ọmọ ẹ̀yìn Jésù, ó máa ṣe dáadáa, ìyẹn ò sì ní ya àwọn èèyàn lẹ́nu torí ohun tí wọ́n retí náà nìyẹn. Àmọ́ ọrọ̀ àtàwọn nǹkan tó ní ló ṣe pàtàkì jù sí i. Ní tàwọn èèyàn yòókù, wọ́n gbà pé òótọ́ làwọn ẹ̀kọ́ Jésù, àwọn ẹ̀kọ́ yìí ló sì máa jẹ́ káwọn rí ìyè. Àwọn yìí ni wọ́n kà sí “ẹni ìkẹyìn,” àmọ́ ní báyìí, wọ́n ti ń di “ẹni àkọ́kọ́.” Lọ́jọ́ iwájú, wọ́n máa bá Jésù jọba lọ́run, wọ́n á sì ṣàkóso lórí aráyé nínú Párádísè.

  • Àpèjúwe Àwọn Òṣìṣẹ́ Ọgbà Àjàrà
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
    • Jésù ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ fáwọn tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀ ní Pèríà pé “ọ̀pọ̀ àwọn ẹni àkọ́kọ́ máa di ẹni ìkẹyìn, àwọn ẹni ìkẹyìn sì máa di ẹni àkọ́kọ́.” (Mátíù 19:30) Kí ohun tó ń sọ lè túbọ̀ yé wọn, ó sọ àpèjúwe kan nípa àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà àjàrà, ó ní:

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́