-
Ọjọ́ Ọ̀la Wo Ni Ó Wà Fún Àwọn Àgùntàn àti Ewúrẹ́?Ilé-Ìṣọ́nà—1995 | October 15
-
-
3. Ṣáájú nínú ìjíròrò rẹ̀, kí ni Jesu sọ pé yóò jẹ yọ kété lẹ́yìn tí ìpọ́njú ńlá náà bá ti bẹ̀rẹ̀?
3 Jesu sọ àsọtẹ́lẹ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ apàfiyèsí tí yóò ṣẹlẹ̀ “lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ lẹ́yìn” ìbẹ́sílẹ̀ ìpọ́njú ńlá, àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí a ń retí. Ó wí pé, nígbà náà ni “àmì Ọmọkùnrin ènìyàn” yóò fara hàn. Èyí yóò nípa jíjinlẹ̀ lórí “gbogbo awọn ẹ̀yà ilẹ̀-ayé” tí wọn yóò “rí Ọmọkùnrin ènìyàn tí ń bọ̀ lórí àwọsánmà ọ̀run pẹlu agbára ati ògo ńlá.” Ọmọkùnrin ènìyàn yóò wà pẹ̀lú “awọn áńgẹ́lì rẹ̀.” (Matteu 24:21, 29-31)a Kí ni nípa ti òwe àkàwé ti àwọn àgùntàn àti ewúrẹ́? Àwọn Bibeli òde òní fi í sí orí 25, ṣùgbọ́n ó jẹ́ apá kan èsì Jesu, tí ó pèsè àwọn kúlẹ̀kúlẹ̀ àlàyé síwájú sí i nípa bíbọ̀ rẹ̀ nínú ògo, tí ó sì darí àfiyèsí sórí ṣíṣe ìdájọ́ “gbogbo awọn orílẹ̀-èdè.”—Matteu 25:32.
-
-
Ọjọ́ Ọ̀la Wo Ni Ó Wà Fún Àwọn Àgùntàn àti Ewúrẹ́?Ilé-Ìṣọ́nà—1995 | October 15
-
-
ṢÀKÍYÈSÍ ÀWỌN ÌJỌRA
Matteu 24:29-31 Matteu 25:31-33
Lẹ́yìn tí ìpọ́njú ńlá náà bẹ̀rẹ̀, Ọmọkùnrin ènìyàn dé
-