-
Awọn Igbokegbodo Ti A Mú Gbooro Sii Nigba Wíwàníhìn-ín KristiIlé-Ìṣọ́nà—1993 | May 1
-
-
15 Ṣakiyesi awọn ọrọ-akiyesi rẹ̀ ninu Matteu 25:31-33 pe: “Nigba ti Ọmọ eniyan yoo wá ninu ògo rẹ̀, ati gbogbo awọn angẹli mimọ pẹlu rẹ̀, nigba naa ni yoo jokoo lori ìtẹ́ ògo rẹ̀: niwaju rẹ̀ ni a o sì kó gbogbo orilẹ-ede jọ: yoo sì yà wọn si ọ̀tọ̀ kuro ninu araawọn gẹgẹ bi oluṣọ-agutan ti i ya agutan rẹ̀ kuro ninu ewurẹ: oun o sì fi agutan si ọwọ ọtun rẹ̀, ṣugbọn awọn ewurẹ si ọwọ́ òsì.”
-
-
Awọn Igbokegbodo Ti A Mú Gbooro Sii Nigba Wíwàníhìn-ín KristiIlé-Ìṣọ́nà—1993 | May 1
-
-
17. Eeṣe ti ipo-ọran lonii fi ni jẹpataki ti o jinlẹ fun gbogbo eniyan?
17 Ninu owe naa, Ọba-Oluṣọ-Agutan naa fi awọn ẹni-bi-aguntan si apa ọ̀tún rẹ̀ ati awọn ẹni-bi-ewurẹ si apa òsì rẹ̀. Apa ọ̀tún naa wá jásí idajọ ti o ní abajade titẹnilọrun—ìyè ayeraye. Apa òsì duro fun idajọ ti kò tẹnilọrun—iyẹn ni ti iparun ayeraye. Ipinnu Ọba naa nipa ọ̀ràn naa ní awọn abajade ti o rinlẹ niti ijẹpataki.
-