-
Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Ọlọ́run?Jí!—2012 | April
-
-
Jésù sọ pé: “Nítorí náà, kí ẹ máa gbàdúrà ní ọ̀nà yìí: ‘Baba wa tí ń bẹ ní ọ̀run, kí orúkọ rẹ di sísọ di mímọ́. Kí ìjọba rẹ dé. Kí ìfẹ́ rẹ ṣẹ, gẹ́gẹ́ bí ti ọ̀run, lórí ilẹ̀ ayé pẹ̀lú. Fún wa lónìí oúnjẹ wa fún ọjọ́ òní; kí o sì dárí àwọn gbèsè wa jì wá, gẹ́gẹ́ bí àwa pẹ̀lú ti dárí ji àwọn ajigbèsè wa. Má sì mú wa wá sínú ìdẹwò, ṣùgbọ́n dá wa nídè kúrò lọ́wọ́ ẹni burúkú náà.’”—Mátíù 6:9-13.
-
-
Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Gbàdúrà sí Ọlọ́run?Jí!—2012 | April
-
-
“Má sì mú wa wá sínú ìdẹwò, ṣùgbọ́n dá wa nídè kúrò lọ́wọ́ ẹni burúkú náà.” “Ẹni burúkú náà” ni Sátánì Èṣù, tá a tún ń pè ní “Adẹniwò náà.” (Mátíù 4:3) Nítorí pé a jẹ́ aláìpé, a nílò ìrànlọ́wọ́ Ọlọ́run ká lè dojú ìjà kọ Èṣù àti àwọn èèyàn tó ń ṣojú fún un.—Máàkù 14:38.
-