ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìdí Tá A Fi Ń Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi
    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022 | January
    • 2 Lọ́dọọdún, a máa ń dara pọ̀ mọ́ ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù èèyàn kárí ayé láti ṣe Ìrántí Ikú Kristi ní àyájọ́ ọjọ́ tó kú torí pé a nífẹ̀ẹ́ rẹ̀. (1 Pét. 1:8) A máa ń pé jọ láti ṣe Ìrántí Ikú ẹni tó fi ẹ̀mí rẹ̀ rà wá pa dà kó lè gbà wá sílẹ̀ lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú. (Mát. 20:28) Kódà, Jésù fẹ́ káwa ọmọlẹ́yìn rẹ̀ máa ṣe Ìrántí Ikú òun. Ní alẹ́ tó ṣáájú ọjọ́ tí Jésù kú, ó dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀, ó sì pàṣẹ pé: “Ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”​—Lúùkù 22:19.

  • Ìdí Tá A Fi Ń Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi
    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2022 | January
    • b Kó o lè mọ̀ sí i nípa májẹ̀mú tuntun àti májẹ̀mú Ìjọba, wo àpilẹ̀kọ náà, “Ẹ̀yin Yóò Di ‘Ìjọba Àwọn Àlùfáà’” nínú Ilé Ìṣọ́ October 15, 2014, ojú ìwé 15-17.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́