ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jésù Sọ̀rọ̀ Nípa Ọrọ̀
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
    • Àwọn wo ni kó máa wá Ìjọba Ọlọ́run? Jésù jẹ́ ká mọ̀ pé àwùjọ èèyàn kékeré kan tó jẹ́ olóòótọ́ ló máa ṣe bẹ́ẹ̀, Bíbélì pè wọ́n ní “agbo kékeré.” Tó bá yá, àwọn ọmọ ẹ̀yìn máa mọ̀ pé ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì (144,000) ni iye wọn. Kí ló wà nípamọ́ fún wọn? Jésù fi dá wọn lójú pé: “Baba yín ti fọwọ́ sí i láti fún yín ní Ìjọba náà.” Àwùjọ yìí ò ní máa lé ohun tí ayé ń lé, kàkà bẹ́ẹ̀, ohun tó máa gbà wọ́n lọ́kàn ni bí wọ́n á ṣe ní “ìṣúra tí kò lè kùnà láé sí ọ̀run,” níbi tí wọ́n ti máa jọba pẹ̀lú Kristi.—Lúùkù 12:32-34.

  • Jésù Ní Kí Ìríjú Olóòótọ́ Náà Múra Sílẹ̀
    Jésù—Ọ̀nà, Òtítọ́ Àti Ìyè
    • Jésù ṣàlàyé pé “agbo kékeré” nìkan ló máa wọ Ìjọba ọ̀run. (Lúùkù 12:32) Àmọ́ ó yẹ kẹ́ni tó bá máa nírú àǹfààní yìí fọwọ́ pàtàkì mú un. Kódà, Jésù tẹnu mọ́ ọn pé ó ṣe pàtàkì kí ẹnì kan ní èrò tó tọ́ tó bá fẹ́ wà nínú Ìjọba náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́