ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • “Ọrùn Mi Mọ́ Kúrò Nínú Ẹ̀jẹ̀ Gbogbo Èèyàn”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
    • Pọ́ọ̀lù àtàwọn tí wọ́n jọ ń rìnrìn àjò ń wọ ọkọ̀ ojú omi. Àwọn alàgbà ìjọ Éfésù gbá Pọ́ọ̀lù mọ́ra wọ́n sì ń sunkún.

      “Gbogbo wọn bú sẹ́kún.”​—Ìṣe 20:37

      22. Kí ló mú káwọn alàgbà ìjọ Éfésù nífẹ̀ẹ́ Pọ́ọ̀lù gan-an?

      22 Pọ́ọ̀lù nífẹ̀ẹ́ àwọn ará gan-an, ìyẹn sì mú káwọn náà nífẹ̀ẹ́ ẹ̀. Kódà, nígbà tí Pọ́ọ̀lù fẹ́ máa lọ, “gbogbo wọn bú sẹ́kún, wọ́n gbá Pọ́ọ̀lù mọ́ra, wọ́n sì fẹnu kò ó lẹ́nu tìfẹ́tìfẹ́.” (Ìṣe 20:37, 38) Bákan náà lónìí, àwọn Kristẹni tòótọ́ mọyì àwọn tó dà bíi Pọ́ọ̀lù wọ́n sì máa ń nífẹ̀ẹ́ wọn gan-an, torí pé ṣe nirú àwọn ẹni bẹ́ẹ̀ máa ń lo àkókò, okun àtàwọn ohun ìní wọn nítorí àwọn ará. Ní báyìí tá a ti gbé àpẹẹrẹ rere Pọ́ọ̀lù yẹ̀ wò, ó hàn kedere pé kò sọ àsọdùn, kò sì gbéra ga nígbà tó sọ pé: “Ọrùn mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀jẹ̀ gbogbo èèyàn.”​—Ìṣe 20:26.

  • “Ọrùn Mi Mọ́ Kúrò Nínú Ẹ̀jẹ̀ Gbogbo Èèyàn”
    “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run”
Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́