ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Pọ́ọ̀lù Fìgboyà Wàásù Níwájú Àwọn Lóókọ-Lóókọ
    Ilé Ìṣọ́—1998 | September 1
    • Jésù wá gbéṣẹ́ fún Sọ́ọ̀lù láti wàásù “àwọn ohun tí ìwọ ti rí àti àwọn ohun tí èmi yóò mú kí o rí nípa mi” fún àwọn ènìyàn àwọn orílẹ̀-èdè. Pọ́ọ̀lù ṣàlàyé pé òun tiraka taápọntaápọn láti ṣe iṣẹ́ àyànfúnni òun ní kíkún. Síbẹ̀, ó sọ fún Àgírípà pé, “tìtorí nǹkan wọ̀nyí ni àwọn Júù fi gbá mi mú nínú tẹ́ńpìlì, tí wọ́n sì gbìdánwò láti pa mí.” Pọ́ọ̀lù fọ̀ràn lọ ìfẹ́ tí Àgírípà ní sí ìsìn àwọn Júù, nípa títẹnu mọ́ ọn pé ìwàásù òun ní gidi “kò sọ nǹkan kan àyàfi àwọn ohun tí àwọn Wòlíì àti Mósè sọ pé yóò ṣẹlẹ̀” nípa ikú Mèsáyà náà àti àjíǹde rẹ̀.—Ìṣe 26:15-23.

  • Pọ́ọ̀lù Fìgboyà Wàásù Níwájú Àwọn Lóókọ-Lóókọ
    Ilé Ìṣọ́—1998 | September 1
Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́