-
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Gálátíà, Éfésù, Fílípì àti KólósèIlé Ìṣọ́—2008 | August 15
-
-
6:2—Kí ni “Òfin Kristi”? Òfin yìí ni gbogbo ẹ̀kọ́ tí Jésù fi kọ́ni àtàwọn àṣẹ tó pa. Ní pàtàkì, àṣẹ tó pa pé káwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ‘nífẹ̀ẹ́ ara wọn lẹ́nì kìíní-kejì.’ (Jòh. 13:34)
-