-
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Títù, Fílémónì àti HébérùIlé Ìṣọ́—2008 | October 15
-
-
15, 16—Kí nìdí tí Pọ́ọ̀lù kò fi sọ fún Fílémónì pé kó sọ Ónẹ́símù dòmìnira? Pọ́ọ̀lù ò fẹ́ kúrò nídìí iṣẹ́ tí Ọlọ́run gbé lé e lọ́wọ́, ìyẹn ‘wíwàásù ìjọba Ọlọ́run àti kíkọ́ni láwọn ohun tó jẹ mọ́ Jésù Kristi Olúwa.’ Nítorí náà, kò fẹ́ láti lọ́wọ́ nínú ọ̀rọ̀ àárín ẹrú àti ọ̀gá rẹ̀ tàbí irú àwọn ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀.—Ìṣe 28:31.
-
-
Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Títù, Fílémónì àti HébérùIlé Ìṣọ́—2008 | October 15
-
-
15, 16. A ò gbọ́dọ̀ jẹ́ káwọn ipò tí kò bára dé nígbèésí ayé mú ká máa ṣàníyàn ju bó ti yẹ lọ. Èyí á ṣe wá láǹfààní gan-an bó ṣe rí nínú ọ̀rọ̀ ti Ónẹ́símù.
-