ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • sjj orin 133
  • Sin Jèhófà Nígbà Ọ̀dọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sin Jèhófà Nígbà Ọ̀dọ́
  • “Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sin Jèhófà Nígbà Èwe
    Kọrin sí Jèhófà
  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ǹjẹ́ Ẹ̀ Ń múra Sílẹ̀ Fún Ọjọ́ Ọ̀la?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Nípìn-ín Nínú Ayọ̀ Tó Wà Nínú Fífúnni!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
  • Ogún Ṣíṣeyebíye Jù Lọ
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
Àwọn Míì
“Fi Ayọ̀ Kọrin” sí Jèhófà
sjj orin 133

ORIN 133

Sin Jèhófà Nígbà Ọ̀dọ́

Bíi Ti Orí Ìwé

(Oníwàásù 12:1)

  1. 1. Jèhófà fẹ́ràn àwa ọ̀dọ́ gan-an.

    Tọkàntọkàn sì la fi ń jọ́sìn rẹ̀.

    Ó dájú pé ó ń fiyè síṣẹ́ wa,

    Yóò sì bù kún wa jálẹ̀ ayé wa.

  2. 2. Àwa ọ̀dọ́ ń bọ̀wọ̀ fún òbí wa,

    A sì ń fi hàn pé a nífẹ̀ẹ́ wọn gan-an.

    Èyí ń jẹ́ kí inú wọn dùn sí wa,

    A sì túbọ̀ ń sún mọ́ Jáà, Ọ̀rẹ́ wa.

  3. 3. Káwa ọ̀dọ́ rántí Ọlọ́run wa.

    Kí òtítọ́ máa jinlẹ̀ lọ́kàn wa.

    Tá a bá fi ayé wa sin Jèhófà,

    Inú rẹ̀ yóò dùn, yóò sì bù kún wa.

(Tún wo Sm. 71:17; Ìdárò 3:27; Éfé. 6:​1-3.)

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́