ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Rírí Ọrọ̀ Tootọ Ni Hong Kong
    Ilé-Ìṣọ́nà—1993 | May 15
    • gidigidi ninu ijẹrii opopona. Wọn tun lọ sọdọ awọn eniyan ni ibi iṣẹ wọn nipa kíkésí awọn oṣiṣẹ ọfiisi, oluṣabojuto ṣọọbu, awọn àgbẹ̀, ati awọn ọkunrin ti ń bọ̀ lati odò ẹja pipa ni Òkun South China.

      A lè sọ nitootọ pe “ikore pọ̀, ṣugbọn awọn alagbaṣe kò tó nǹkan” ni Hong Kong. (Matteu 9:37) Ní lọ́ọ́lọ́ọ́, ipin awọn Ẹlẹ́rìí si iye awọn eniyan olugbe jẹ́ 1 si 2,300. Ní mimọriri ijẹkanjukanju iṣẹ ikore naa, iye ti o fẹrẹẹ tó 600 ninu 2,600 awọn akede Ijọba nibẹ ni wọn jẹ́ aṣaaju-ọna, tabi oniwaasu ihinrere alakooko kikun. Awọn Ẹlẹ́rìí Jehofa ni Hong Kong, bi awọn wọnni ti wọn wà ní ibomiran, mọ daju pe “ibukun Oluwa ní múniílà.” (Owe 10:22) Fun idi yii, wọn ń ṣiṣẹ kára lati ran ọpọlọpọ awọn eniyan sii lọwọ ninu ẹgbẹ́-àwùjọ alaasiki yẹn lati rí ọrọ̀ tootọ.

  • Iwọ Ha Ń Tọ Jehofa Lẹhin Lẹ́kùn-ún-rẹ́rẹ́ Bi?
    Ilé-Ìṣọ́nà—1993 | May 15
    • Iwọ Ha Ń Tọ Jehofa Lẹhin Lẹ́kùn-ún-rẹ́rẹ́ Bi?

      “OLÓDODO láyà bi kinniun.” (Owe 28:1) Wọn ń lo igbagbọ, wọn ń fi igbọkanle gbarale Ọ̀rọ̀ Ọlọrun, wọn sì ń fi ìgboyà lọ siwaju ninu iṣẹ-isin Jehofa ni oju ewu eyikeyii.

      Nigba ti awọn ọmọ Israeli wà ni Sinai lẹhin ti Ọlọrun dá wọn nídè kuro ninu oko-ẹrú Egipti ni ọrundun kẹrindinlogun B.C.E., awọn ọkunrin meji ni pataki fihàn pe awọn láyà bi kinniun. Wọn tun fi

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́