ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • B12-A Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kìíní)
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • B12-A

      Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kìíní)

      Àtẹ ìsọfúnni tó tọ́ka sí ọdún 33 S.K., ọdún tí Jésù kú.

      Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀

      Àwòrán ilẹ̀ Jerúsálẹ́mù àti agbègbè rẹ̀. A tọ́ka sí àwọn ibi tá a mọ̀, àtàwọn ibi tó ṣeé ṣe kó jẹ́. 1. Tẹ́ńpìlì. 2. Ọgbà Gẹ́tísémánì. 3. Ààfin Gómìnà. 4. Ilé Káyáfà. 5. Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò. 6. Adágún Omi Bẹtisátà. 7. Adágún Omi Sílóámù. 8. Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn. 9. Gọ́gọ́tà. 10. Ákélídámà.
      1. Tẹ́ńpìlì

      2. Ọgbà Gẹ́tísémánì (?)

      3. Ààfin Gómìnà

      4. Ilé Káyáfà (?)

      5. Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?)

      6. Adágún Omi Bẹtisátà

      7. Adágún Omi Sílóámù

      8. Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?)

      9. Gọ́gọ́tà (?)

      10. Ákélídámà (?)

      Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́: Nísàn 8 | Nísàn 9 | Nísàn 10 | Nísàn 11

      Nísàn 8 (Sábáàtì)

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)

      • Ó dé sí Bẹ́tánì lọ́jọ́ mẹ́fà ṣáájú ọjọ́ Ìrékọjá

      • Jòhánù 11:55–12:1

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

      Nísàn 9

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      • Ó bá Símónì adẹ́tẹ̀ jẹun

      • Màríà da òróró náádì sí Jésù lórí

      • Àwọn Júù wá wo Jésù àti Lásárù

      • Mátíù 26:6-13

      • Máàkù 14:3-9

      • Jòhánù 12:2-11

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      • Jésù gun kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àwọn èèyàn tínú wọn ń dùn tẹ́ ẹ̀wù àwọ̀lékè wọn àti imọ̀ ọ̀pẹ sójú ọ̀nà.

        Ó wọ Jerúsálẹ́mù tiyì-tẹ̀yẹ

      • Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì

      • Mátíù 21:1-11, 14-17

      • Máàkù 11:1-11

      • Lúùkù 19:29-44

      • Jòhánù 12:12-19

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

      Nísàn 10

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      • Ó sun Bẹ́tánì mọ́jú

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      • Jésù dojú tábìlì àwọn tó ń pàrọ̀ owó dé.

        Ìrìn àjò ní kùtùkùtù sí Jerúsálẹ́mù

      • Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́

      • Jèhófà sọ̀rọ̀ látọ̀run

      • Mátíù 21:18, 19; 21:12, 13

      • Máàkù 11:12-19

      • Lúùkù 19:45-48

      • Jòhánù 12:20-50

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

      Nísàn 11

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      • Jésù ń bá àwọn kan lára àpọ́sítélì rẹ̀ sọ̀rọ̀ lórí Òkè Ólífì. Tẹ́ńpìlì wà lọ́ọ̀ọ́kán lẹ́yìn wọn.

        Ó kọ́ni ní tẹ́ńpìlì, ó lo àpèjúwe

      • Ó dẹ́bi fún àwọn Farisí

      • Ó kíyè sí ọrẹ tí opó kan ṣe

      • Lórí Òkè Ólífì, ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ ìparun Jerúsálẹ́mù àti àmì ìgbà tó máa wà níhìn-ín

      • Mátíù 21:19–25:46

      • Máàkù 11:20–13:37

      • Lúùkù 20:1–21:38

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

  • B12-B Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kejì)
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • B12-B

      Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kejì)

      Àtẹ ìsọfúnni tó tọ́ka sí ọdún 33 S.K., ọdún tí Jésù kú.

      Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀

      Àwòrán ilẹ̀ Jerúsálẹ́mù àti agbègbè rẹ̀. A tọ́ka sí àwọn ibi tá a mọ̀, àtàwọn ibi tó ṣeé ṣe kó jẹ́. 1. Tẹ́ńpìlì. 2. Ọgbà Gẹ́tísémánì. 3. Ààfin Gómìnà. 4. Ilé Káyáfà. 5. Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò. 6. Adágún Omi Bẹtisátà. 7. Adágún Omi Sílóámù. 8. Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn. 9. Gọ́gọ́tà. 10. Ákélídámà
      1. Tẹ́ńpìlì

      2. Ọgbà Gẹ́tísémánì (?)

      3. Ààfin Gómìnà

      4. Ilé Káyáfà (?)

      5. Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?)

      6. Adágún Omi Bẹtisátà

      7. Adágún Omi Sílóámù

      8. Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?)

      9. Gọ́gọ́tà (?)

      10. Ákélídámà (?)

      Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́: Nísàn 12 | Nísàn 13 | Nísàn 14 | Nísàn 15 | Nísàn 16

      Nísàn 12

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      • Júdásì Ìsìkáríọ́tù ń gbìmọ̀ pẹ̀lú àwọn aṣáájú ẹ̀sìn.

        Òun àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ wà níbi tó pa rọ́rọ́

      • Júdásì ṣètò bí wọ́n ṣe máa mú Jésù

      • Mátíù 26:1-5, 14-16

      • Máàkù 14:1, 2, 10, 11

      • Lúùkù 22:1-6

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

      Nísàn 13

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      • Pétérù àti Jòhánù ń tẹ̀ lé ọkùnrin tó ru ìṣà omi.

        Pétérù àti Jòhánù múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá

      • Jésù àtàwọn àpọ́sítélì yòókù dé ní ọjọ́rọ̀

      • Mátíù 26:17-19

      • Máàkù 14:12-16

      • Lúùkù 22:7-13

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

      Nísàn 14

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      •  Jésù àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ olóòótọ́ jọ wà nídìí tábìlì nígbà Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa.

        Òun àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ jẹ Ìrékọjá

      • Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì

      • Ó ní kí Júdásì máa lọ

      • Ó dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀

      • Mátíù 26:20-35

      • Máàkù 14:17-31

      • Lúùkù 22:14-38

      • Jòhánù 13:1–17:26

      • Jésù wà lókè, ó ń wo Pétérù nígbà tó sẹ́ ẹ níṣojú àwọn èèyàn tó wà nínú àgbàlá.

        Júdásì fi í hàn, wọ́n sì mú un ní ọgbà Gẹ́tísémánì (2)

      • Àwọn àpọ́sítélì sá

      • Ó jẹ́jọ́ níwájú Sàhẹ́ndìrìn nílé Káyáfà (4)

      • Pétérù sẹ́ Jésù

      • Mátíù 26:36-75

      • Máàkù 14:32-72

      • Lúùkù 22:39-65

      • Jòhánù 18:1-27

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      • Wọ́n dé adé ẹ̀gún sí Jésù lórí, wọ́n wọ aṣọ aláwọ̀ pọ́pù fún un, Pílátù sì ń fi han àwọn èèyàn tínú ń bí.

        Ó tún jẹ́jọ́ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (8)

      • Wọ́n mú un lọ sọ́dọ̀ Pílátù (3), lẹ́yìn náà sọ́dọ̀ Hẹ́rọ́dù (5), wọ́n tún dá a pa dà sọ́dọ̀ Pílátù (3)

      • Nikodémù, Jósẹ́fù ará Arimatíà, àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn míì fẹ́ lọ tẹ́ Jésù sí ibòjì.

        Wọ́n dájọ́ ikú fún un, wọ́n sì pa á ní Gọ́gọ́tà (9)

      • Ó kú ní nǹkan bí aago mẹ́ta ọ̀sán

      • Wọ́n gbé òkú rẹ̀ lọ sin

      • Mátíù 27:1-61

      • Máàkù 15:1-47

      • Lúùkù 22:66–23:56

      • Jòhánù 18:28–19:42

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

      Nísàn 15 (Sábáàtì)

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      • Pílátù gbà pé kí wọ́n fi àwọn ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ sàréè Jésù

      • Mátíù 27:62-66

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

      Nísàn 16

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      • Wọ́n ra èròjà tó ń ta sánsán púpọ̀ sí i láti sin òkú rẹ̀

      • Máàkù 16:1

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

      • Màríà Magidalénì ń yọjú wo ibojì Jésù tó ti ṣófo.

        Ó jíǹde

      • Ó fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn

      • Mátíù 28:1-15

      • Máàkù 16:2-8

      • Lúùkù 24:1-49

      • Jòhánù 20:1-25

      ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

      Pa dà sí ìbẹ̀rẹ̀

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́