ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • scl ojú ìwé 95-96
  • Iyèméjì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Iyèméjì
  • Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
Àwọn Ẹsẹ Bíbélì Tó Lè Ran Àwa Kristẹni Lọ́wọ́
scl ojú ìwé 95-96

Iyèméjì

Tá a bá ń ronú pé bóyá la lè wúlò fún Jèhófà, àkóbá wo nìyẹn lè ṣe fún wa?

Nọ 11:14, 15; 1Ọb 19:1-4; Job 3:3; Jer 15:10

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Da 10:8-11, 18, 19—Wòlíì Dáníẹ́lì ò lókun mọ́, àmọ́ nígbà tí áńgẹ́lì kan rán an létí pé ó ṣeyebíye lójú Jèhófà, ó pa dà lókun

    • Mt 10:29-31—Jésù sọ àpèjúwe kan nípa àwọn ológoṣẹ́ láti jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀rọ̀ wa jẹ Jèhófà lógún, ó sì nífẹ̀ẹ́ wa

  • Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó lè tù wá nínú:

    • Jer 31:3; Jo 6:44; Heb 6:10; 1Pe 1:18, 19; 1Jo 3:19, 20

    • Tún wo Sm 56:8; Jer 29:11

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́