“Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run” “Jẹ́rìí Kúnnákúnná Nípa Ìjọba Ọlọ́run” Àwòrán Ilẹ̀ Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Lẹ́tà Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ÌBẸ̀RẸ̀ ORÍ 1 “Ẹ Lọ, Kí Ẹ Máa Sọ Àwọn Èèyàn . . . Di Ọmọ Ẹ̀yìn” APÁ 1 APÁ 1 • ÌṢE 1:1–6:7 “Ẹ Ti Fi Ẹ̀kọ́ Yín Kún Jerúsálẹ́mù” (Ìṣe 5:28) ORÍ 2 “Ẹ Ó sì Jẹ́ Ẹlẹ́rìí Mi” ORÍ 3 Wọ́n “Kún fún Ẹ̀mí Mímọ́” ORÍ 4 ‘Àwọn Èèyàn Tí Ò Kàwé àti Gbáàtúù’ ORÍ 5 “A Gbọ́dọ̀ Ṣègbọràn sí Ọlọ́run Gẹ́gẹ́ Bí Alákòóso Dípò Èèyàn” APÁ 2 APÁ 2 • ÌṢE 6:8–9:43 “Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Ṣe Inúnibíni Tó Lágbára Sí Ìjọ” ORÍ 6 Sítéfánù “Kún fún Oore Ọlọ́run àti Agbára” ORÍ 7 Fílípì Kéde “Ìhìn Rere Nípa Jésù” ORÍ 8 Ìjọ “Wọnú Àkókò Àlàáfíà” APÁ 3 APÁ 3 • ÌṢE 10:1–12:25 “Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè . . . Gba Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run” ORÍ 9 “Ọlọ́run Kì Í Ṣe Ojúsàájú” ORÍ 10 “Ọ̀rọ̀ Jèhófà Ń Gbilẹ̀” APÁ 4 APÁ 4 • ÌṢE 13:1–14:28 “Ẹ̀mí Mímọ́ Rán Wọn Jáde” ORÍ 11 Wọ́n ní “Ìdùnnú àti Ẹ̀mí Mímọ́ ní Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́” ORÍ 12 Wọ́n “Fi Ìgboyà Sọ̀rọ̀ Nípasẹ̀ Àṣẹ Jèhófà” APÁ 5 APÁ 5 • ÌṢE 15:1-35 “Àwọn Àpọ́sítélì àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ” ORÍ 13 ‘Lẹ́yìn Tí Wọ́n Jiyàn Díẹ̀’ ORÍ 14 “A Ti Fìmọ̀ Ṣọ̀kan” APÁ 6 APÁ 6 • ÌṢE 15:36–18:22 “Ní Báyìí, Jẹ́ Ká Pa Dà Lọ Bẹ Àwọn Ará Wò” ORÍ 15 Pọ́ọ̀lù “Ń Fún Àwọn Ìjọ Lókun” ORÍ 16 “Sọdá Wá sí Makedóníà” ORÍ 17 ‘Ó Bá Wọn Fèròwérò Látinú Ìwé Mímọ́’ ORÍ 18 Ẹ Wá Ọlọ́run, Kẹ́ Ẹ sì Rí I Ní Ti Gidi ORÍ 19 “Máa Sọ̀rọ̀ Nìṣó, Má sì Dákẹ́” APÁ 7 APÁ 7 • ÌṢE 18:23–21:17 Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé” ORÍ 20 “Ọ̀rọ̀ Jèhófà Ń Gbilẹ̀ Nìṣó, Ó sì Ń Borí” Lójú Àtakò ORÍ 21 “Ọrùn Mi Mọ́ Kúrò Nínú Ẹ̀jẹ̀ Gbogbo Èèyàn” ORÍ 22 “Kí Ìfẹ́ Jèhófà Ṣẹ” APÁ 8 APÁ 8 • ÌṢE 21:18–28:31 ‘Wọ́n Wàásù Ìjọba Ọlọ́run Láìsí Ìdíwọ́’ ORÍ 23 “Ẹ Gbọ́ Ẹjọ́ Tí Mo Fẹ́ Rò fún Yín” ORÍ 24 “Mọ́kàn Le!” ORÍ 25 “Mo Ké Gbàjarè sí Késárì!” ORÍ 26 “Kò sí Ìkankan Lára Yín Tó Máa Ṣègbé” ORÍ 27 “Jẹ́rìí Kúnnákúnná” ÌPÁRÍ ORÍ 28 “Títí Dé Ibi Tó Jìnnà Jù Lọ ní Ayé” Atọ́ka Àwòrán