HÁBÁKÚKÙ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Wòlíì náà ké pe Jèhófà pé kó ran òun lọ́wọ́ (1-4) “Jèhófà, báwo ló ṣe máa pẹ́ tó?” (2) ‘Kí nìdí tí o fi fàyè gba ìnilára?’ (3) Ọlọ́run lo àwọn ará Kálídíà láti ṣèdájọ́ (5-11) Wòlíì náà bẹ Jèhófà (12-17) ‘Ọlọ́run mi, ìwọ kì í kú’ (12) ‘O ti mọ́ jù láti máa wo ohun búburú’ (13) 2 “Èmi yóò máa ṣọ́nà kí n lè mọ ohun tí yóò sọ” (1) Èsì tí Jèhófà fún wòlíì náà (2-20) ‘Ṣáà máa retí ìran náà’ (3) Ìṣòtítọ́ yóò mú kí olódodo máa wà láàyè (4) Nǹkan márùn-ún tó mú kí àwọn ará Kálídíà gbé (6-20) Gbogbo ayé yóò ní ìmọ̀ nípa Jèhófà (14) 3 Wòlíì náà bẹ Jèhófà pé kó gbé ìgbésẹ̀ (1-19) Ọlọ́run yóò gba àwọn ẹni àmì òróró rẹ̀ là (13) Máa yọ̀ nítorí Jèhófà láìka wàhálà sí (17, 18)