HÁGÁÌ OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ 1 Jèhófà bá wọn wí torí wọn ò tún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-11) ‘Ṣé àsìkò yìí ló yẹ kí ẹ máa gbé inú àwọn ilé tí ẹ fi pákó ṣe lọ́ṣọ̀ọ́?’ (4) “Ẹ kíyè sí àwọn ohun tí ẹ̀ ń ṣe” (5) Wọ́n ń fún irúgbìn tó pọ̀, àmọ́ díẹ̀ ni wọ́n ń kórè (6) Àwọn èèyàn náà fetí sí ohùn Jèhófà (12-15) 2 Ògo yóò kún inú tẹ́ńpìlì kejì (1-9) Ọlọ́run yóò mi gbogbo orílẹ̀-èdè jìgìjìgì (7) Àwọn ohun iyebíye nínú gbogbo orílẹ̀-èdè yóò wọlé wá (7) Ọlọ́run bù kún wọn torí pé wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́ (10-19) Ìjẹ́mímọ́ kò lè ràn (10-14) Iṣẹ́ tí Ọlọ́run rán sí Serubábélì (20-23) ‘Èmi yóò ṣe ọ́ bí òrùka èdìdì’ (23)