ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • nwt ojú ìwé 1794-1795
  • B14-B Owó àti Ìdíwọ̀n

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • B14-B Owó àti Ìdíwọ̀n
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Ìsọ̀rí
  • Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù
  • Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
B14-B Owó àti Ìdíwọ̀n

B14-B

Owó àti Ìdíwọ̀n

Bíi Ti Orí Ìwé

Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Lédè Hébérù

Gérà (Ṣékélì 1⁄20)

Gíráàmù 0.57 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.01835

Gérà 10 = Bíkà 1

Bíkà

Gíráàmù 5.7 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.1835

Bíkà 2 = Ṣékélì 1

Píìmù

Gíráàmù 7.8 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.2508

Píìmù 1 = Ṣékélì 2⁄3

Ṣékélì, òṣùwọ̀n táwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi ń díwọ̀n bí nǹkan ṣe wúwo

Ìdíwọ̀n ṣékélì

Ṣékélì

Gíráàmù 11.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.367

Ṣékélì 50 = Mínà 1

Mínà

Gíráàmù 570 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 18.35

Mínà 60 = Tálẹ́ńtì 1

Tálẹ́ńtì

Kìlógíráàmù 34.2 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 1,101

Dáríkì

Dáríkì (ti Páṣíà, wúrà)

Gíráàmù 8.4 / 0.27 Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì

Ẹ́sírà 8:27

Owó àti Ìdíwọ̀n Nínú Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì

Lẹ́pítónì

Lẹ́pítónì (Ti àwọn Júù, bàbà tàbí idẹ)

Kúádíránì 1⁄2

Lúùkù 21:2

Kúádíránì

Kúádíránì (Ti àwọn ará Róòmù, bàbà tàbí idẹ)

Lẹ́pítónì 2

Mátíù 5:26

Ásáríò

Ásáríò (Ti àwọn Róòmù àtàwọn ìlú abẹ́ wọn, bàbà tàbí idẹ)

Kúádíránì 4

Mátíù 10:29

Dínárì

Dínárì (Ti àwọn Róòmù, fàdákà)

Kúádíránì 64

Gíráàmù 3.85 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.124

Mátíù 20:10

= Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 1 (Wákàtí 12)

Dírákímà

Dírákímà (Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà)

Gíráàmù 3.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.109

Lúùkù 15:8

= Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 1 (12 hours)

Dírákímà méjì alápapọ̀

Dírákímà méjì alápapọ̀ (Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà)

Dírákímà 2

Gíráàmù 6.8 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.218

Mátíù 17:24

= Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 2

Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ ti Áńtíókù àti dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ ti Tírè

Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ ti Tírè (Ṣékélì fàdákà ti Tírè)

Dírákímà mẹ́rin alápapọ̀ (Ti àwọn Gíríìkì, fàdákà; wọ́n tún ń pè é ní owó sítátà fàdákà)

Dírákímà 4

Gíráàmù 13.6 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 0.436

Mátíù 17:27

= Owó Iṣẹ́ Ọjọ́ 4

Owó dírákímà tí wọ́n tò jọ pelemọ, 100 dírákímà ni mínà kan

Mínà

Dírákímà 100

Gíráàmù 340 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 10.9

Lúùkù 19:13

= nǹkan bí owó iṣẹ́ 100 ọjọ́

Owó ẹyọ fàdákà tí wọ́n tò jọ yìí jẹ́ tálẹ́ńtì kan

Tálẹ́ńtì

Mínà 60

Kìlógíráàmù 20.4 / Tọ́ọ̀nù ọ́ǹsì 654

Mátíù 18:24

Ìfihàn 16:21

= nǹkan bí owó iṣẹ́ 20 ọdún

Nǹkan tó lè gba ìwọ̀n owó pọ́n-ùn àwọn ará Róòmù

Ìwọ̀n Pọ́n-ùn (ti àwọn ará Róòmù)

Gíráàmù 327 / Ọ́ǹsì 11.5

Jòhánù 12:3

“Ìwọ̀n pọ́n-ùn kan òróró onílọ́fínńdà, ojúlówó náádì”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́