ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • nwt ojú ìwé 26-ojú ìwé 27
  • Ìbéèrè 15: Báwo lo ṣe lè láyọ̀?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ìbéèrè 15: Báwo lo ṣe lè láyọ̀?
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ìbéèrè 15: Báwo lo ṣe lè láyọ̀?

ÌBÉÈRÈ 15

Báwo lo ṣe lè láyọ̀?

Inú ọmọbìnrin kan ń dùn bó ṣe fẹ́ fún bàbá rẹ̀ ní àwòrán kan tó yà fún un

“Oúnjẹ tí a fi nǹkan ọ̀gbìn sè níbi tí ìfẹ́ wà sàn ju akọ màlúù àbọ́sanra níbi tí ìkórìíra wà.”

Òwe 15:17

“Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ, Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní, Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.”

Àìsáyà 48:17

“Aláyọ̀ ni àwọn tó ń wá ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run, torí Ìjọba ọ̀run jẹ́ tiwọn.”

Mátíù 5:3

“Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”

Mátíù 22:39

“Bí ẹ ṣe fẹ́ kí àwọn èèyàn ṣe sí yín gẹ́lẹ́ ni kí ẹ máa ṣe sí wọn.”

Lúùkù 6:31

“Aláyọ̀ ni àwọn tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń pa á mọ́!”

Lúùkù 11:28

“Tí ẹnì kan bá tiẹ̀ ní nǹkan rẹpẹtẹ, àwọn ohun tó ní kò lè fún un ní ìwàláàyè.”

Lúùkù 12:15

“Torí náà, tí a bá ti ní oúnjẹ àti aṣọ, àwọn nǹkan yìí máa tẹ́ wa lọ́rùn.”

1 Tímótì 6:8

“Ayọ̀ púpọ̀ wà nínú fífúnni ju èyí tó wà nínú rírígbà lọ.”

Ìṣe 20:35

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́