ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g 4/12 ojú ìwé 32
  • Kí Ni Èrò Rẹ Nípa Jésù?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kí Ni Èrò Rẹ Nípa Jésù?
  • Jí!—2012
Jí!—2012
g 4/12 ojú ìwé 32

Kí Ni Èrò Rẹ Nípa Jésù?

Ojú wo lo sábà máa ń fi wo Jésù, sé bí ìkókó kan tàbí ẹni tó ń kú lọ tàbí Ọba tí a gbé ga?

Bíbélì jẹ́ kí á mọ̀ pé Ọba alágbára ni Jésù. Àmọ́, báwo nìyẹn ṣe kàn ọ́?

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló gbà gbọ́ pé Jésù kú fún àwọn. Àmọ́, báwo ni ikú ọkùnrin kan ní nǹkan bí ẹgbẹ̀rún méjì [2,000] ọdún sẹ́yìn ṣe lè mú kí àwọn èèyàn ní ìyè lóde òní?

A fi ọ̀yàyà pè ọ́ pé kó o wá gbọ́ bá a ṣe máa fi Ìwé Mímọ́ dáhùn àwọn ìbéèrè yìí. A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nígbà tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà bá pé jọ láti ṣe Ìrántí Ikú Kristi. Lọ́dún yìí, a máa ṣe Ìrántí Ikú Kristi ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ Thursday, April 5.

Jọ̀wọ́ béèrè ibi tí wọ́n ti máa ṣe é àti àkókò tí wọ́n máa ṣe é lọ́wọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ládùúgbò rẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́