ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 9A
Jèhófà Mú Àwọn Ìlérí Rẹ̀ Ṣẹ—Nígbà Àtijọ́
1. Kò ní sí ìbọ̀rìṣà nínú ìjọsìn mímọ́
2. Wọ́n á pa dà sí ilẹ̀ tó lọ́ràá
3. Jèhófà máa tẹ́wọ́ gba àwọn ọrẹ
4. Àwọn ọkùnrin olóòótọ́ máa múpò iwájú
5. Wọ́n á jọ́sìn Ọlọ́run níṣọ̀kan nínú tẹ́ńpìlì