ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w11 12/15 ojú ìwé 32
  • Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2011

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2011
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Ìsọ̀rí
  • ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
  • ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
  • BÍBÉLÌ
  • ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
  • ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
  • JÈHÓFÀ
  • JÉSÙ KRISTI
  • Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
w11 12/15 ojú ìwé 32

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2011

Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

A Jẹ́ “Olùgbé fún Ìgbà Díẹ̀” Nínú Ayé Búburú, 11/15

Bá A Ṣe Lè Fi Ọwọ́ Pàtàkì Mú Iṣẹ́ Ìsìn Wa sí Jèhófà, 4/15

Bọ̀wọ̀ fún Ìgbéyàwó Tó Jẹ́ Ẹ̀bùn Ọlọ́run, 1/15

“Èso Ti Ẹ̀mí” Ń Fi Ògo fún Ọlọ́run, 4/15

Ẹ Fi Ìfaradà Sá Eré Ìje Náà, 9/15

Ẹ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà bí Òpin Ti Ń Sún Mọ́lé, 3/15

Ẹ Kọ́ Àwọn Míì Kí Wọ́n Lè Tóótun fún Àǹfààní Iṣẹ́ Ìsìn, 11/15

Ẹ Máa Lépa Àlàáfíà, 8/15

Ẹ Máa Rìn ní Ìbámu Pẹ̀lú Ẹ̀mí Kẹ́ Ẹ Lè Jogún Ìyè àti Àlàáfíà, 11/15

Ẹ Máa Ṣe Àwọn Ìpinnu Tó Máa Gbé Orúkọ Ọlọ́run Ga, 4/15

“Ẹ Máa Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo Ọlọ́run Tí Ń Bẹ Lábẹ́ Àbójútó Yín,” 6/15

Ẹ̀mí Mímọ́ Ń Fún Wa Lágbára Ká Lè Borí Àdánwò Èyíkéyìí, 1/15

Ẹ̀mí Mímọ́ Ń Fún Wa Lágbára Ká Lè Kojú Ìdẹwò Ká sì Borí Ìrẹ̀wẹ̀sì, 1/15

Ẹ̀mí Mímọ́ Ni Ọlọ́run Lò Nígbà Ìṣẹ̀dá, 2/15

Ẹ̀mí Ọlọ́run Darí Àwọn Kristẹni ní Ọ̀rúndún Kìíní Ó sì Ń Darí Àwa Náà Lónìí, 12/15

Ẹ̀mí Ọlọ́run Darí Àwọn Olóòótọ́ Ayé Ìgbàanì, 12/15

Ẹ̀mí Ọlọ́run Ni Kó O Gbà, Má Ṣe Gba Ẹ̀mí Ayé, 3/15

“Ẹ Ní Ẹ̀mí Ìkanisí fún Àwọn Tí Ń Ṣiṣẹ́ Kára Láàárín Yín,” 6/15

Ẹ Ran Àwọn Ọkùnrin Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Tẹ̀ Síwájú Nípa Tẹ̀mí, 11/15

Ẹ Sáré . . . Kí Ọwọ́ Yín Lè Tẹ̀ Ẹ́,” 9/15

Ẹ Wà Lójúfò Bíi Ti Jeremáyà, 3/15

Ẹ Wà ní Ìmúratán! 3/15

Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni—“Ẹ Wà Lójúfò,” 5/15

Ẹ̀yin Ìdílé Kristẹni—“Ẹ Wà Ní Ìmúratán,” 5/15

Fi Gbogbo Ọkàn Rẹ Nífẹ̀ẹ́ Òdodo, 2/15

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, “Ọlọ́run Ìtùnú Gbogbo,” 10/15

Ìgbọ́kànlé Kíkún Nínú Jèhófà Ń Mú Ká Ní Ìgboyà, 5/15

Ìhìn Rere Tó Yẹ Kí Gbogbo Èèyàn Gbọ́, 6/15

‘Ìjìnlẹ̀ Ọgbọ́n Ọlọ́run Mà Pọ̀ O!’ (Ro 11), 5/15

Ìmọ̀ràn Ọlọgbọ́n Fáwọn Tí Kò Ṣègbéyàwó Àtàwọn Tó Ṣègbéyàwó, 10/15

Jèhófà Ń Fìfẹ́ Tọ́ Wa Sọ́nà, Ṣé Wàá Tẹ̀ Lé Ìtọ́sọ́nà Rẹ̀? 7/15

Jèhófà Ni Ìpín Mi, 9/15

Jèhófà, “Ọlọ́run Tí Ń Fúnni Ní Àlàáfíà,” 8/15

Kí Ni Ìsinmi Ọlọ́run? 7/15

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Ọlọ́run Máa Darí Wa? 12/15

Lo Ẹ̀bùn Wíwà Láìní Ọkọ Tàbí Aya Lọ́nà Tó Dára Jù Lọ, 1/15

‘Má Ṣe Gbára Lé Òye Tìrẹ,’ 11/15

Ǹjẹ́ O Kórìíra Ìwà Àìlófin? 2/15

Ǹjẹ́ Ò Ń Fi Jèhófà Ṣe Ìpín Rẹ? 9/15

Ọlọ́run Dámọ̀ràn Ìfẹ́ Rẹ̀ fún Wa, 6/15

Rírí Ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run Ló Máa Mú Ká Jogún Ìyè Àìnípẹ̀kun, 2/15

“Sá Di Orúkọ Jèhófà,” 1/15

Ṣé Àpẹẹrẹ Rere Ló Jẹ́ fún Ẹ àbí Ìkìlọ̀? 12/15

Ṣé Eré Ìtura Tó O Yàn Máa Ṣe Ẹ́ Láǹfààní? 10/15

Ṣé Jèhófà Mọ̀ Ẹ́? 9/15

Ṣé Ò Ń Jẹ́ Kí Ẹ̀mí Ọlọ́run Máa Darí Rẹ? 4/15

Ṣé O Ti Wọnú Ìsinmi Ọlọ́run? 7/15

Ṣé Wàá Gbọ́ Ìkìlọ̀ Tó Ṣe Kedere Tí Jèhófà Ń Fún Wa? 7/15

Ta Ló Ṣe Pàtàkì Jù Lọ ní Ìgbésí Ayé Rẹ? 5/15

“Tu Gbogbo Àwọn Tí Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú,” 10/15

Wọ́n Retí Mèsáyà, 8/15

Wọ́n Rí Mèsáyà! 8/15

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

“Àǹfààní Ìfúnni Onínúrere” (ọrẹ), 11/15

Àwọn Àpéjọ Àgbègbè “Kí Ìjọba Ọlọ́run Dé!” 6/1

Àwọn Àpéjọ Àgbègbè Nílẹ̀ Rọ́ṣíà, 3/1

Àwọn Ìsọfúnni Tó Máa Ń Wà Nínú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Wa Ọdọọdún, 8/15

Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 2/1, 8/1

Gbèjà Orúkọ Rere (Rọ́ṣíà), 5/1

Ìdí fún Ayọ̀ Yíyọ̀ (ètò), 3/15

Ilé Ẹjọ́ Dá Àwọn Èèyàn Jèhófà Láre! (Rọ́ṣíà), 7/15

Ilé Ìṣọ́ Tá A Fi Èdè Gẹ̀ẹ́sì Tó Rọrùn Kọ (ìwé ìròyìn), 7/15

Ìpàdé Ọdọọdún, 8/15

Lẹ́tà Láti . . . , 3/1, 6/1, 9/1, 12/1

Ṣé Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Gba Ìtọ́jú Lọ́dọ̀ Àwọn Dókítà? 2/1

“Wọ́n Kọ̀ Jálẹ̀, Ó Yẹ Ká Bọ̀wọ̀ fún Wọn” (Ìjọba Násì, Orílẹ̀-èdè Jámánì), 10/1

BÍBÉLÌ

Abala Àwọn Ọ̀dọ́, 1/1, 3/1, 5/1, 7/1, 9/1, 11/1

Àwọn Wo Lára Àwọn Tó Kọ Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì Ló Wà ní Pẹ́ńtíkọ́sì Ọdún 33 Sànmánì Kristẹni? 12/1

Ìgbà Tí Wọ́n Kọ Ọ́, 6/1

Ìsapá Zamora Láti Túmọ̀ Ìwé Mímọ́ Lọ́nà Tó Péye, 12/1

Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà, 2/1, 4/1, 5/1, 7/1, 8/1, 10/1, 11/1

Mẹ́fà Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Tó Ń Ṣẹ Lójú Wa, 5/1

Olivétan—‘Onírẹ̀lẹ̀ Tó Túmọ̀’ Bíbélì, 9/1

Ṣé Kíkẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Máa Ń Gbádùn Mọ́ Ẹ? 5/15

Wákàtí Ọjọ́, 5/1

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

Bí O Ṣe Lè Yan Ọ̀rẹ́ Rere? 12/1

Bíi Ti Fíníhásì Bó O Bá Dojú Kọ Àwọn Ipò Tó Nira, 9/15

Ẹ Jẹ́ Ká Jọ Máa Yọ̀! 10/15

Ẹ Má Ṣe Fi Èrò Èké Tan Ara Yín Jẹ, 3/15

Fòye Mọ Ẹ̀rí Tó Fi Hàn Pé Ọlọ́run Ń Tọ́ Wa Sọ́nà, 4/15

Ìbéèrè Tó Dá Lórí Bíbélì, Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe Tí Mo Bá Nílò Ìmọ̀ràn Nípa Ìṣòro Kan? 10/15

“Ìgbà Nínífẹ̀ẹ́ àti Ìgbà Kíkórìíra,” 12/1

‘Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ,’ 2/15

Ìjọsìn Ìdílé, 8/15

Íńtánẹ́ẹ̀tì, 8/15

Ipa Tí Ọmọ Lè Ní Lórí Àjọṣe Ọkọ àti Aya, 5/1

Ìsapá Náà Tó Bẹ́ẹ̀ Ó Jù Bẹ́ẹ̀ Lọ! (Ìjọsìn Ìdílé), 2/15

Kí Làwọn Bàbá Lè Ṣe Tí Àjọṣe Wọn Pẹ̀lú Ọmọkùnrin Wọn Kò Fi Ní Bà Jẹ́? 11/1

Kí Ló Lè Mú Kí Ìdílé Rẹ Jẹ́ Aláyọ̀? 10/1

Kí Ló Lè Mú Kí Ìgbéyàwó Wà Pẹ́ Títí? 2/1

Kọ́ Àwọn Ọmọ Láti Máa Bọ̀wọ̀ Fúnni, 2/15

Kọ́ Àwọn Ọmọ ní Ohun Tó Tọ́ Nípa Ìbálòpọ̀, 2/1

Kọ́ Ọmọ Rẹ, 2/1, 4/1, 6/1, 8/1, 10/1, 12/1

Má Ṣe Jẹ́ Kí Àìlera Ba Ayọ̀ Rẹ Jẹ́, 12/15

Má Ṣe Kọ Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́ Sílẹ̀ Láé, 3/15

“Máa Bá A Nìṣó ní Ṣíṣọ́nà” 10/15

Máa Bọ̀wọ̀ fún Ọkọ Tàbí Aya Rẹ, 8/1

Máa Ṣe Àṣàrò Lórí Ohun tí Jèhófà Ti Ṣe fún Ẹ, 1/15

Mọyì Àwọn Ìbùkún Tó O Ní? 2/15

“Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí sí Rere,” 6/15

Olóòótọ́ Nínú Ayé Aláìṣòótọ́, 4/15

Owó Orí, 9/1

Ṣé Ó Yẹ Kí Òbí Kọ́ Àwọn Ọmọ Nípa Ìbálòpọ̀? 11/1

Ṣó Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Ṣe Ìrìbọmi? 6/15

Tọkọtaya, Ẹ Kọ́ Bí Ẹ Ṣe Máa Jẹ́ Ẹni Tẹ̀mí, 11/1

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

“Alábòójútó Rere àti Ọ̀rẹ́ Wa Ọ̀wọ́n” (J. Barr), 5/15

“Aláìlera Ni Mí Báyìí, àmọ́ Mi Ò Ní Wà Bẹ́ẹ̀ Títí Láé!” (S. van der Monde), 11/15

Bí Ọmọbìnrin Jẹ́fútà (J. Soans), 12/1

Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà Ń Fún Mi Láyọ̀ (F. Rusk), 10/15

Kíka Bíbélì Lójoojúmọ́ Ti Fún Mi Lókun (M. Leroy), 9/15

Mo Bẹ̀rù Ikú, àmọ́ Ìyè “Lọ́pọ̀ Yanturu” Ni Mò Ń Retí Báyìí (P. Gatti), 7/15

Mo Dúpẹ́ Pé Àdánwò Kò Mú Kí N Dẹ́kun Láti Máa Sin Jèhófà (M. de Jonge-van den Heuvel), 1/15

Mo Fẹ́ràn Ìrìn-Àjò àti Eré Ìfarapitú (Z. Dimitrova), 6/1

Mo Ti Jàǹfààní Látinú Àwọn Ìyípadà Tí Mo Ṣe (J. Thompson), 12/15

Mo Ti Rí Ọ̀pọ̀ Ohun Rere (A. Bonno), 4/15

JÈHÓFÀ

Àwọn Òfin Tó Ń Darí Àwọn Nǹkan Tó Wà Lójú Ọ̀run, 7/1

Irọ́ Márùn-ún Táwọn Èèyàn Ń Pa Mọ́ Ọlọ́run, 10/1

Kí Ló Yẹ Kí Àwọn Ọmọdé Kọ́? 8/1

Kí Ni Ọlọ́run Ní Lọ́kàn fún Ilẹ̀ Ayé? 4/1

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìwà Ibi àti Ìjìyà? 5/1

Kí Nìdí Tó Fi Jẹ́ Pé Àparò Ni Ọlọ́run Fi Bọ́ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì? 9/1

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Ọlọ́run? 1/1

Ní Ibì Kan Tó Ń Gbé? 8/1

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ? 1/1

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Mọ̀ Pé Ádámù àti Éfà Máa Dẹ́ṣẹ̀? 1/1

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Ń Gbé Ẹ̀yà Ìran Kan Ga Ju Òmíràn Lọ? 7/1

Ǹjẹ́ Ọlọ́run Ní Ètò Kan Tó Gbé Kalẹ̀? 6/1

Òfin Ọlọ́run Ń Ṣe Wá Láǹfààní, 1/1

Orúkọ Níbi Àfonífojì (Orílẹ̀-èdè Switzerland), 1/15

Sún Mọ́ Ọlọ́run, 1/1, 2/1, 3/1, 4/1, 5/1, 6/1, 7/1, 8/1, 9/1, 10/1, 11/1, 12/1

Ṣé Ọlọ́run Ló Dá Èṣù? 3/1

Ta Ni Ọlọ́run? 2/1

JÉSÙ KRISTI

Bá A Ṣe Lè Máa Tọ Kristi Aṣáájú Pípé Náà Lẹ́yìn, 5/15

Gbólóhùn Náà “Ìwọ Fúnra Rẹ Wí I,” 6/1

Ibí tí Jésù Ti Wá; Bó Ṣe Gbé Ìgbé Ayé Rẹ̀; Ìdí Tó Fi Kú, 4/1

Ìgbẹ́jọ́, 4/1

Ǹjẹ́ Ó Ṣeé Ṣe Láti Sọ Ní Pàtó Iye Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà? 8/15

Ṣé Òótọ́ Ni Jésù Kú Lórí Àgbélébùú? 3/1

Ta Ni Jésù Kristi? 3/1

Wákàtí Tí Wọ́n Kan Jésù Kristi Mọ́gi, 11/15

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

“Agbo Ilé Késárì” (Flp 4:22), 3/1

Àjálù—Ṣé Ọlọ́run Ló Fi Ń Pọ́n Aráyé Lójú? 12/1

Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ (Jo 10:22), 9/1

Àwọn Àpọ́sítélì Mú Ọ̀pá, Kí Wọ́n sì Wọ Sálúbàtà, 3/15

Àwọn Tó Ń Pààrọ̀ Owó Nínú Tẹ́ńpìlì, 10/1

Bárábà, 4/1

Báwo Làwọn Júù Ṣe Ń Mọ Iye Aago Tó Lù Nígbà Tí Ilẹ̀ Bá Ti Ṣú? 8/1

Báwo Ni Ipò Òṣì Ṣe Máa Dópin? 6/1

Bí Wọ́n Ṣe Ń Rí Owó Ná Sórí Àwọn Nǹkan Tí Wọ́n Ń Ṣe ní Tẹ́ńpìlì, 11/1

Ìdí Tí Sátánì Fi Lo Ejò, 1/1

Igi Ólífì Wúlò Gan-an, 10/1

Ìgbà Wo Ni Wọ́n Pa Jerúsálẹ́mù Run? 10/1, 11/1

“Ìhìn Rere Ìjọba” Náà, 3/1

Ilé Tí Nebukadinésárì Kọ́, 11/1

“Ilẹ̀ Kan Tí Ń Ṣàn fún Wàrà àti Oyin,” 3/1

Ìrètí Wà fún Àwọn Tó Ti Kú, 6/1

Ìrìbọmi fún Àwọn Ọmọ Ọwọ́, 10/1

Irú Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Wo Ni Wọ́n Lè Torí Rẹ̀ Pààyàn bí Wọ́n Ṣe Pa Jésù? 4/1

Irú Ilé Wo Ló Ṣeé Ṣe Kí Ábúrámù Gbé? 1/1

Jéhù Jà fún Ìjọsìn Mímọ́, 11/15

Késárì, Kí Ló Túmọ̀ Sí? 7/1

Kí Lo Lè Fi Dá Ẹ̀sìn Tòótọ́ Mọ̀? 8/1

Kí Ló Mú Kí Mósè Bínú sí Àwọn Ọmọ Áárónì? (Le 10:16-20), 2/15

Kí Ni Amágẹ́dọ́nì? 9/1

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìbálòpọ̀? 11/1

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run? 7/1

Kí Nìdí Tó Fi Jẹ́ Pé Lẹ́bánónì Ni Sólómọ́nì Ti Kó Igi Gẹdú? 2/1

“Mo Ti Gbà Gbọ́” (Màtá), 4/1

‘Mú Àwọn Àkájọ Ìwé Wá àti Àwọn Ìwé Awọ,’ 6/15

Mú Kí Ìgbésí Ayé Rẹ Dára, 7/1

Ǹjẹ́ Ayé Máa Pa Run ní Ọdún 2012? 12/1

Ǹjẹ́ Ìwàláàyè Títí Láé Nínú Párádísè Máa Súni? 5/1

Ó Fara Da Ìjákulẹ̀ (Sámúẹ́lì), 1/1

Ó Gbèjà Àwọn Èèyàn Ọlọ́run (Ẹ́sítérì), 10/1

Ó Rí Ìtùnú Gbà Lọ́dọ̀ Ọlọ́run (Èlíjà), 7/1

Ojú Wo Ni Àwọn Aṣáájú Ẹ̀sìn Júù ní Ọjọ́ Jésù Fi Ń Wo Àwọn Gbáàtúù? 7/1

Omi Nígbà Ẹ̀ẹ̀rùn Lórílẹ̀-Èdè Ísírẹ́lì, 1/1

“Oríṣi Ohun Ọ̀gbìn Méje” Lára Ohun Ọ̀gbìn Ilẹ̀ Tí Ó Dára Náà, 9/1

Orúkọ Tí Wọ́n Fi Òǹtẹ̀ Lù Sára Amọ̀ Láyé Ìgbàanì, 5/1

Owó (ní àkókò tí wọ́n ń kọ Bíbélì), 5/1

“Òwú Aláwọ̀ Rírẹ̀dòdò Ti Kòkòrò Kókọ́sì,” 12/1

Ọgbà Édẹ́nì, 1/1

Ọkùnrin Kan Tí Ó Tẹ́ Ọkàn Jèhófà Lọ́rùn, 9/1

“Ọmọge, àní Àwọn Ọmọge” (Onw 2:8), 3/15

Pétérù Dé Sílé Ọkùnrin Kan Tó Jẹ́ Oníṣẹ́ Awọ, 6/1

Pípèéṣẹ́, 2/1

Ṣe Bó O Ti Mọ, 6/1

Ṣé Gbogbo Kristẹni Olóòótọ́ Ló Ń Lọ sí Ọ̀run? 6/1

Ṣé Ibi Tí Wọ́n Ti Ń Fi Iná Dáni Lóró Ni Gẹ̀hẹ́nà? 4/1

Ṣé Inú Ọkàn Ni Ìjọba Ọlọ́run Wà? 3/1

Ṣé Ò Ń Múra Sílẹ̀ fún Ọjọ́ Tó Ṣe Pàtàkì Jù Lọ Nínú Ọdún? 2/1

Ṣé Òótọ́ Ni Ábúráhámù Ní Ràkúnmí? 6/15

Ṣé Póòpù Ló “Rọ́pò Pétérù”? 8/180

Ṣíṣú Opó, 3/1

Ta Ló Lè Túmọ̀ Àsọtẹ́lẹ̀? 12/1

Ta Ló Ń Ṣàkóso Ayé? 9/1

Tẹ́tẹ́ Títa, 3/1

“Títàpá sí Ọ̀pá Kẹ́sẹ́” (Iṣe 26:14), 8/1

Wọ́n Rí Ará Ìlà Oòrùn Éṣíà Kan ní Ítálì Àtijọ́, 1/1

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́