ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • w24 August ojú ìwé 32
  • Ohun Tá A Fẹ́ Kẹ́yin Òǹkàwé Wa Mọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Fẹ́ Kẹ́yin Òǹkàwé Wa Mọ̀
  • Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
w24 August ojú ìwé 32

Ohun Tá A Fẹ́ Kẹ́yin Òǹkàwé Wa Mọ̀

Ẹ̀yin Òǹkàwé Wa Ọ̀wọ́n

Nínú Ilé Ìṣọ́ yìí, a máa jíròrò àpilẹ̀kọ márùn-ún tó máa dáhùn àwọn ìbéèrè tó tẹ̀ lé e yìí:

  • Àkọ́kọ́, ètò wo ni Jèhófà ṣe kí àwa ọmọ ẹ̀ lè máa sá fún ẹ̀ṣẹ̀, ká sì máa ṣohun tó fẹ́?

  • Ìkejì, kí lẹni tó dẹ́ṣẹ̀ máa ṣe kó lè ronú pìwà dà tọkàntọkàn, báwo sì ni Jèhófà ṣe máa ràn án lọ́wọ́?

  • Ìkẹta, báwo ni Jèhófà ṣe ní kí ìjọ tó wà ní Kọ́ríńtì bójú tó ọ̀rọ̀ ẹni tó dẹ́ṣẹ̀ tí ò ronú pìwà dà?

  • Ìkẹrin, báwo làwọn alàgbà ṣe máa ran àwọn tó dẹ́ṣẹ̀ tó burú jáì lọ́wọ́ lásìkò wa yìí?

  • Ìkarùn-ún, lẹ́yìn tí wọ́n bá mú ẹni tí ò ronú pìwà dà kúrò nínú ìjọ, báwo làwọn ará ṣe lè máa fìfẹ́ àti àánú hàn sí ẹni náà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́