Jẹ́nẹ́sísì 37:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àwọn ọmọ Mídíánì ta Jósẹ́fù fún Pọ́tífárì, òṣìṣẹ́ láàfin Fáráò+ àti olórí ẹ̀ṣọ́,+ ní Íjíbítì.