-
Jẹ́nẹ́sísì 41:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àmọ́ nígbà tí ilẹ̀ mọ́, ọkàn rẹ̀ ò balẹ̀. Ó wá ránṣẹ́ pe gbogbo àlùfáà onídán nílẹ̀ Íjíbítì àti gbogbo àwọn amòye ilẹ̀ náà. Fáráò rọ́ àwọn àlá rẹ̀ fún wọn, àmọ́ kò sẹ́nì kankan tó lè túmọ̀ wọn fún Fáráò.
-