ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 4:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Mo wá pàṣẹ pé kí wọ́n kó gbogbo àwọn amòye Bábílónì wá síwájú mi, kí wọ́n lè sọ ìtumọ̀ àlá náà fún mi.+

      7 “Ìgbà yẹn ni àwọn àlùfáà onídán, àwọn pidánpidán, àwọn ará Kálídíà* àti àwọn awòràwọ̀+ wọlé wá. Nígbà tí mo rọ́ àlá náà fún wọn, wọn ò lè sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi.+

  • Dáníẹ́lì 5:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ọba ké jáde pé kí wọ́n ránṣẹ́ pe àwọn pidánpidán, àwọn ará Kálídíà* àti àwọn awòràwọ̀.+ Ọba sọ fún àwọn amòye Bábílónì pé: “Ẹnikẹ́ni tó bá ka ọ̀rọ̀ yìí, tó sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi, a máa fi aṣọ aláwọ̀ pọ́pù wọ̀ ọ́, a máa fi ìlẹ̀kẹ̀ wúrà sí i lọ́rùn,+ ó sì máa di igbá kẹta nínú ìjọba.”+

      8 Gbogbo àwọn amòye ọba wá wọlé, àmọ́ wọn ò lè ka ọ̀rọ̀ náà, wọn ò sì lè sọ ohun tó túmọ̀ sí fún ọba.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́