-
Dáníẹ́lì 2:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àmọ́ tí ẹ bá sọ àlá náà àti ìtumọ̀ rẹ̀, màá fún yín ní ẹ̀bùn, màá san yín lẹ́san, màá sì dá yín lọ́lá lọ́pọ̀lọpọ̀.+ Torí náà, ẹ sọ àlá náà àti ìtumọ̀ rẹ̀ fún mi.”
-