-
Jẹ́nẹ́sísì 39:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà tó yá, ó fi gbogbo ohun tó ní sí ìkáwọ́ Jósẹ́fù, kò sì da ara rẹ̀ láàmú nípa ohunkóhun àfi oúnjẹ tó ń jẹ. Yàtọ̀ síyẹn, Jósẹ́fù taagun, ó sì rẹwà.
-
-
Sáàmù 105:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ó fi í ṣe ọ̀gá lórí agbo ilé rẹ̀
Àti alákòóso lórí gbogbo ohun ìní rẹ̀,+
-