Sáàmù 105:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó rán ọkùnrin kan lọ ṣáájú wọn,Jósẹ́fù, ẹni tí wọ́n tà lẹ́rú.+ 18 Wọ́n fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ de ẹsẹ̀ rẹ̀,*+Wọ́n fi irin de ọrùn rẹ̀;* Ìṣe 7:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn olórí ìdílé náà jowú Jósẹ́fù,+ wọ́n sì tà á sí Íjíbítì.+ Àmọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀,+ 10 ó gbà á nínú gbogbo ìpọ́njú rẹ̀, ó ṣe ojúure sí i, ó sì fún un ní ọgbọ́n níwájú Fáráò ọba Íjíbítì. Ó yàn án láti ṣàkóso Íjíbítì àti gbogbo ilé rẹ̀.+
17 Ó rán ọkùnrin kan lọ ṣáájú wọn,Jósẹ́fù, ẹni tí wọ́n tà lẹ́rú.+ 18 Wọ́n fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ de ẹsẹ̀ rẹ̀,*+Wọ́n fi irin de ọrùn rẹ̀;* Ìṣe 7:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn olórí ìdílé náà jowú Jósẹ́fù,+ wọ́n sì tà á sí Íjíbítì.+ Àmọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀,+ 10 ó gbà á nínú gbogbo ìpọ́njú rẹ̀, ó ṣe ojúure sí i, ó sì fún un ní ọgbọ́n níwájú Fáráò ọba Íjíbítì. Ó yàn án láti ṣàkóso Íjíbítì àti gbogbo ilé rẹ̀.+
9 Àwọn olórí ìdílé náà jowú Jósẹ́fù,+ wọ́n sì tà á sí Íjíbítì.+ Àmọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ̀,+ 10 ó gbà á nínú gbogbo ìpọ́njú rẹ̀, ó ṣe ojúure sí i, ó sì fún un ní ọgbọ́n níwájú Fáráò ọba Íjíbítì. Ó yàn án láti ṣàkóso Íjíbítì àti gbogbo ilé rẹ̀.+