-
Jẹ́nẹ́sísì 42:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Kí ẹ sì mú àbúrò yín tó kéré jù wá sọ́dọ̀ mi, kí n lè mọ̀ pé olódodo ni yín, pé ẹ kì í ṣe amí. Màá wá dá arákùnrin yín pa dà fún yín, ẹ sì lè máa ṣòwò ní ilẹ̀ yìí.’”
-