Jẹ́nẹ́sísì 42:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Nígbà tí Jékọ́bù gbọ́ pé ọkà wà ní Íjíbítì,+ ó sọ fún àwọn ọmọ rẹ̀ pé: “Kí ló dé tí ẹ kàn ń wo ara yín lójú?” 2 Ó ní: “Mo ti gbọ́ pé ọkà wà ní Íjíbítì. Ẹ lọ rà á wá níbẹ̀ fún wa, ká lè wà láàyè, ká má bàa kú.”+
42 Nígbà tí Jékọ́bù gbọ́ pé ọkà wà ní Íjíbítì,+ ó sọ fún àwọn ọmọ rẹ̀ pé: “Kí ló dé tí ẹ kàn ń wo ara yín lójú?” 2 Ó ní: “Mo ti gbọ́ pé ọkà wà ní Íjíbítì. Ẹ lọ rà á wá níbẹ̀ fún wa, ká lè wà láàyè, ká má bàa kú.”+