Ìṣe 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, Jósẹ́fù ránṣẹ́ pe Jékọ́bù bàbá rẹ̀ àti gbogbo mọ̀lẹ́bí rẹ̀ láti ibẹ̀,+ gbogbo wọn* lápapọ̀ jẹ́ márùndínlọ́gọ́rin (75).+
14 Torí náà, Jósẹ́fù ránṣẹ́ pe Jékọ́bù bàbá rẹ̀ àti gbogbo mọ̀lẹ́bí rẹ̀ láti ibẹ̀,+ gbogbo wọn* lápapọ̀ jẹ́ márùndínlọ́gọ́rin (75).+