-
Jẹ́nẹ́sísì 43:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ẹ mú owó ìlọ́po méjì dání; kí ẹ sì mú owó tí wọ́n dá pa dà sí ẹnu àpò+ yín dání. Bóyá àṣìṣe ni.