-
Nọ́ńbà 26:44, 45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Àwọn ọmọ Áṣérì+ nìyí ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Ímúnà, ìdílé àwọn ọmọ Ímúnà; látọ̀dọ̀ Íṣífì, ìdílé àwọn ọmọ Íṣífì; látọ̀dọ̀ Bẹráyà, ìdílé àwọn ọmọ Bẹráyà; 45 nínú àwọn ọmọ Bẹráyà: látọ̀dọ̀ Hébà, ìdílé àwọn ọmọ Hébà; látọ̀dọ̀ Málíkíélì, ìdílé àwọn ọmọ Málíkíélì.
-