ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 30:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Líà sì sọ pé: “Ayọ̀ mi kún! Ó dájú pé àwọn ọmọbìnrin máa pè mí ní aláyọ̀.”+ Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Áṣérì.*+

  • Jẹ́nẹ́sísì 35:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Àwọn ọmọkùnrin tí Sílípà ìránṣẹ́ Líà bí ni Gádì àti Áṣérì. Àwọn ni ọmọkùnrin Jékọ́bù, tí wọ́n bí fún un ní Padani-árámù.

  • Jẹ́nẹ́sísì 46:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Àwọn ọmọkùnrin Áṣérì+ ni Ímúnà, Íṣífà, Íṣífì àti Bẹráyà, pẹ̀lú Sírà arábìnrin wọn.

      Àwọn ọmọ Bẹráyà ni Hébà àti Málíkíélì.+

  • 1 Kíróníkà 7:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Àwọn ọmọkùnrin Áṣérì ni Ímúnà, Íṣífà, Íṣífì àti Bẹráyà,+ pẹ̀lú Sírà+ arábìnrin wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́