Jẹ́nẹ́sísì 7:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí ní ọjọ́ méje òní, èmi yóò rọ òjò+ sórí ayé fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru,+ màá sì run gbogbo ohun alààyè tí mo dá kúrò lórí ilẹ̀.”+ 1 Pétérù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 àwọn tó ṣàìgbọràn nígbà tí Ọlọ́run ń fi sùúrù dúró* ní àwọn ọjọ́ Nóà,+ lákòókò tí wọ́n ń kan ọkọ̀ áàkì,+ tí a fi gba àwọn èèyàn díẹ̀ là nígbà ìkún omi, ìyẹn ọkàn* mẹ́jọ.+
4 Torí ní ọjọ́ méje òní, èmi yóò rọ òjò+ sórí ayé fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru,+ màá sì run gbogbo ohun alààyè tí mo dá kúrò lórí ilẹ̀.”+
20 àwọn tó ṣàìgbọràn nígbà tí Ọlọ́run ń fi sùúrù dúró* ní àwọn ọjọ́ Nóà,+ lákòókò tí wọ́n ń kan ọkọ̀ áàkì,+ tí a fi gba àwọn èèyàn díẹ̀ là nígbà ìkún omi, ìyẹn ọkàn* mẹ́jọ.+